Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje...
Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP. Báyìí ni àwon èrò àti àwon ará ìlú se pariwo mó Ààre ilé-ìgbìmò Asòfin àti olùdíje...
View ArticleGideon Okeke àti Chidera Udueze se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won
Òsèré okùnrin tí gbogbo èèyàn Gideon Okeke ti se ìgbéyàwó ìbílè tàbí ti àbáláyé rè pèlú òkín láwùjo gbogbo eye, è yun ún ìyàwó rè tí ó rewà, orúko ìyàwó rè náà a máa jé chidera. Eléyìí kíì se iró tàbí...
View ArticleSola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí...
Sola Sobowale dàbí egbin bínú aso tí ó wo lo síbi ìfilólè eré orí ìtàgé tí àkolé rè n jé “King of Boys. Ògbóntarìgì tí ó tún jé gbajúgbajà òsèré tí gbogbo èèyàn mò sí Sola Sobowale, wo aso aláràbarà...
View ArticleOkò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé...
Okò bògònì tí a mò sí Bentley ti Linda Ikeji rà fún omo rè tí orúko rè n jé Jayce Jeremi, ti dé sí ìlú èkó. Linda Ikeji ti pin sí orí èro ayélujára láti fi hàn wípé okò tí òhun se ìlérí fún omo òhun...
View ArticleÌmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River...
Ìmú wo egbé òkùnkùn ti ó selè ní ìjoba ìbílè Obanliku ní Ìpínlè Cross River ti mú èmí eni tí won fé mú wo egbé náà lo ní ojó ketàdínl’ógbòn osù òpe odún 2018. Orúko arákùnrin náà a máa jé Miracle....
View ArticlePurity Okojie se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún méfà (6) ní àná:...
Akoni àti ogbóntàrigì òsèré obìnrin, tí a mò sí Mercy Johnson Okojie, tí ó fé omo oba Odi Okojie tí ó sì bí omo méta, Okúnrin kan obìnrin méjì. Mercy Johnson ti se ayeye ojó ìbí fún àkóbí rè, orúko...
View ArticleIka logberi won o gboju lila f’Alawo #EsuIsNotSatan
The ignorants are wicked, they don’t want Yoruba Spirituality to prosper. To buttress my point stated above, i would summarize my message (Oro isiti), delivered at our Temple, Indigene Faith of...
View ArticleOpen Letter to the king of Osogbo – Baba Adigun Olosun
I am using this medium to advice the king of Osogbo to stop harassing and threatening me with his people and his so-called police officers. You sent them to my sister’s house to kidnap me and as they...
View ArticleOriki Olokun
Olokun, orisa that lives in waterShe spreads herself all over the earthOrisa that has no handOrisa that has no legShe uses her power to take your legs out from under youThat makes a small child fall...
View ArticleE jowo e ran wa leti isele inu aworan yii
Eyin ara Abule, e ba ni se akiyesi aworan yii daadaa. Se kii se pe ogbeni yii fee yin ibon AK47 mo obinrin yii lapa ni? E jowo e ran wa leti isele inu aworan yii, asiko wo ni isele yii waye? Agbegbe...
View ArticleOdu, Idin Osogbo, Idin ileke, Idin irete
AA Looking at the Odu, Idin Osogbo, Idin ileke, Idin irete, cast for today’s Ose Ifa, I can declare that our detractors shall be put to shame. Just listen as follows:- Won se ko baje Awo AyeKo lee...
View ArticleYour culture and tradition are not “demonic” as they portray it…
The culture of reciting lineage praises/cognomen(Oríkì) when a child does something praiseworthy is gradually fading in Yoruba land. We will never be Òyìnbó(English). If we lose this valuable culture...
View ArticleYoruba verbs for today
Jókòó= sit downDìde=stand upBẹ̀rẹ̀=crouchKúnlẹ̀=kneel downFò=jumpFòsókè=jump up
View ArticleÀkóṣe Ọ̀ràngún Méjì
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iná awerepèpè, a ó lọ̀ ọ́ kúnná dáadáa, a ó wà ṣa tí yóó gbẹ dáadáa. Ọ̀ràngún méjì ni a ó tẹ̀ ẹ́. A ó pe Ifá sí, a ó fi ṣín gbẹ́rẹ́ la orí já. A ó wà á fi ẹbu Ifá náà rá àwọn ojú gbẹ́rẹ́...
View ArticleWhen will this slander of our cherished heritage, “Esu” stop? #EsuIsNotSatan
Watching Nollywood Yoruba movies sometimes can be annoying.Most common utterances I regard very insulting are stated as follows:- Ti Esu ba fun o ni adie yoo gba malu lowo re If Esu gives you a fowl,...
View ArticleÒsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà...
Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé. Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé se àfihàn ewà rè nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà, tí ó sì dàbí egbin...
View ArticleÀwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom
Àwon méjì pàdánù èmí won nígbà tí àwon omo ìta sun okò àwon INEC ní Akwa-Ibom. Bí ó tilè jé wípé won ti sún ìdìbò síwájú látàrí àwon ìsèlè àifójúrí kan tí àwon tí ó n se ètò ìdìbo se nígbà tí won se...
View Article