Àwon èrò àti ò n wò ran pariwo “Ó tó gé olè” fún Bukola Saraki àti olùdíje fún ilé-ìgbìmò Asòfin ti egbé PDP.
Báyìí ni àwon èrò àti àwon ará ìlú se pariwo mó Ààre ilé-ìgbìmò Asòfin àti olùdíje ilé-ìgbìmò Asòfin fún egbé PDP, tí a mò sí Bukola Saraki.Nígbà tí Rasaq Atunwa lo sí Ajase-ipo ní ìpínlè Kwara.
Àwon èèyàn ìpínlè Kwara ti yarí won sì ti kígbe “ó tó gé” “olè” mo baba lórí, wípé àwon kò tèle mó.
