Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.
Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn. Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò. Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde...
View ArticleTope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú...
Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985. Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi...
View ArticleBánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú...
Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki. Ìròyìn kàyéfì… Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ti se...
View ArticleGómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó...
Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé...
View ArticleMi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.
Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so wípé òun kò le fé okùnrin...
View ArticleÀwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón...
Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó...
View Article#EsuIsNotSatan Walk is here, Save the date !
ATTENTION!!! ATTENTION!!! ATTENTION!!! As it is our custom, the enlightment walk, against the demonization of Esu will be taking place on Monday 24th December. Rally point is at ojuelegba bus stop ....
View ArticleOdu Ogunda bede
Looking at the Odu, “Ogunda bede” cast for today’s Ose Ifa, it can be declared beyond reasonable doubt that Orunmila demonstrated his leadership by example by following divine injunction. Just listen...
View Article#EsuIsNotSatan: Esu Alaagba shrine at Iyanapaja – Photos
Another one done and dusted! Please everyone should help give special thanks to our artist Eletu Fasilat Omolola for a good job well done. I know many would have been seeing this Esu Alaagba shrine at...
View ArticleWhy ex-Arugba cannot live in the Osun temple
The king of Osogbo called a meeting of Osogbo chiefs and Osun temple elders to discuss why ex-Arugba cannot live in the Osun temple. We thrashed it and the oldest ex-Arugba told the gathering that it...
View ArticleAwon Aworan Iyẹdọla Iyaaṣa
Ọpẹ lọwọ Edua fun aṣeyọri iwure ta ṣe, iroko a sẹrọ fun gbogbo wa o, awọn alaṣeku a bawa ṣe, Edua a mu ibeere wa ṣẹ, aṣẹ.IYẸDỌLA_IYAAṢA! ỌKIN ỌLỌJA ẸIYẸ!!!
View ArticleBetween ‘Esu’ and The banker – #EsuIsNotSatan
Discussion on Esu continues. An employed graduate, a Christian, asked his friend, also a graduate but a Babalawo, “why did you quit your good job to serve ‘Esu’ “? The Babalawo answered, ” I get...
View ArticleA Legend is gone: Professor Sophie Oluwole passes on at 83
Ooduarere.com reacts to Professor Sophie Oluwole’s Death. The legendaryphilosopher of Ifa divination has moved on to the land of our ancestors. She wrote the influential book titled SOCRATES AND...
View ArticleOlamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5.
Olamide, Adekunle Gold, Praiz, Do2dtun àti Wizkid ní ibi OLIC 5. Nse ni ó dàbí eni wípé àjòdún odoodún tí a mò sí OLIC 5 ti Olamide àti Wizkid papò sí ojó kan náà, tí a mò sí ojó àná, orúko àríyá...
View ArticleBiodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì.
Biodun Okeowo pín àwòrán tí ó rewà láti se ayeye odún Kérésì. Gbajúgbajà Òsèré bìrin náà tí ólúwa fún ní ewà àti ara tí ó wuyì , orúko rè a máa jé Biodun Okeowo, ìnagije rè a sì máa jé Omo Butty ti fi...
View ArticleArts of Being a Yoruba
We will, from time to time, pay homage to those who advance Yoruba thoughts with important, ground-breaking contributions. Introducing a book by Dr. Adeleke Adeeko, distinguished professor of African...
View ArticleTonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà...
Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà ti Burna Boy. Gbajúgbajà Òsèré obìnrin tí a mò sí Tonto Dikeh, ti pín èrò rè sí orí èro ayélujára látàrí fídíò tí won pín...
View ArticleOwó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè...
Owó ti te àwon gbómogbómo àti àwon Adigunjalè tí ó n da Adamawa àti èèyàn ibè láàmú. Ogbóntarigì gbómogbómo àti àwon adigunjalè tí ó n da àwon èèyàn ati awon olùgbé ìpínlè Adamawa láàmú ni owó àwon...
View ArticleAlàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.
Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí. Alàgbà kan ní ìjo Catholic se oríre wípé èmi rè sì wà láyé nípa tí ikú ti fo orí rè kojá nínu ìjàmbá okò tí ó ní. Gégé bí ìròyìn se so,...
View ArticleIs Esu really Satan? By Babalawo Familusi Awolola
It is alarming to note the level of misinformation that has befallen the Yoruba race in lieu of our inclination towards alien esoteric knowledge. When I see people referring to Esu in derogatory...
View Article