Òsèré obìnrin tí ó tún jé Arewà, tí gbogbo ayé mò sí Adunni Ade se àfihàn ewà ara ré nínú sòkòtò pénpé.
Gbajúgbajà òsèré orí ìtàgé se àfihàn ewà rè nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà, tí ó sì dàbí egbin nínú aso ìwòsún tí a mò sí pyjamas tí ó wò sókè àti sòkòtò pénpé tí ó wò sí ìsàlè, tí ó sì gbé ewà rè hàn.
Ó ya àwòrán náà ní àrà òtò, tí ó sì fi ako si.
