Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mr Harri se ìgbéyawó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar ní ìpínlè Eko.

Arákùnrin kan ní orílè èdè Nìjíríà ti ya òpò èyan lénu látàrí sése ìgbéyàwó pèlú ohun èlò orin tí a mò sí guitar rè. Tí e bá rò wípé e ti ri tán , eléyìí tún ya ni lénu ò. Harri best ti pín sí orí èro...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arákùnrin tí ó n se yahoo ni ó ti ya wèrè nígbá tí bàbá eè kú tán ní ìlú Benin.

Kàyéfì nlá ni ó jé nígbà tí Arákùnrin kan ya wèrè ní ìlú Benin ní ìpínlè Edo. Gégé bí ìròyìn se so, òdókùnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé isé kí á máa fi èro gbáni ni ó n se tí a mò sí Yahoo ni ó n se....

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon Jagunjagun tí a mò sí Soldier ti pa ìko àwon Boko Haram ní Arege, Borno,...

Two Ikò Boko Haram ti fi ojú winá ogun won sì ti bá ogún lo, tí ojú won sì rí méwàá ni ojó kejìlélógbòn osù kokànlá odún 2018 nígbà tí won tún fé se bí ìse won ní Arege ní ìjoba ìbílè Mobbar ní ìpínlè...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn.

Àwòrán télè ti Leo Babarinde Dasilva nígbà tí ó wà ní omo àgbákórùn. Ní àná tí se ojóbò tí àwon eléyìbó n pè ni Thursday, won ni kí àwon wo èyìn wò. Ará ilé BBNaija télè tí a mò sí Leo Babarinde...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Tope Osoba se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún métàlélógbò (33) pèlú...

Temitope Osoba tí gbogbo ènìyàn mò sí Tope Osoba jé òsèré orílè èdè Nìjíríà tí ó sì tún jé olùko eré, won bí i ní ojó kejì osù kejìlá, odún 1985. Ó jé jé akékòó jáde ilé-èkó gíga ifáfitì Olabisi...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú...

Bánà Omo Egbé APC tí ó n lo fún Gómìnà ìpínlè Kwara ni won lè sí iwájú agboolé àwon Saraki. Ìròyìn kàyéfì… Omo egbé APC tí a mò sí Abdulrasaq Abdulrahman, tí ó n díjé fún ipò Gómìnà ìpínlè Kwara ti se...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó...

Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó náà kí ó tó di wípé...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún.

Mi ò le fé okùnrin tí kò bá le bámi sùn fún wákàtí méjìlá sí méèdógún. Arábìnrin kan tí a kò fi taratara mo orúko rè súgbón tí kò le jú omo odún méèdógún sí ogbòn kan ni ó so wípé òun kò le fé okùnrin...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwon tí ó n gbélè sunkún síta fún ìrànlówó nígbà tí àwon adigunjalè jàwón...

Àwon olùgbé Opolo ní Yenagoa ìpínlè Bayelsa ni ìbèrùbojo ti gba okàn won léyìn tí àwon adigunjalè jà won lólè tán. Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè yí kojá ogbòn tí won sì gbé àwon ohun ìjà olóró lówó...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

European Ancestor Versus Oodua Ancestor: Which One Marches Your DNA?

OODUA Ancestors are well over 50,000years old in existence; While European Ancestors conscripted by the Roman Vatican are not more that 5,000years old in existence…. according to Archeological...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Orí ejò

Bí kò bá sí ọpẹ́lọpẹ́ orí, à bá tí mú ejò digi lókoÌtàkùn mà lejòKíni yoo bá ejò ṣẹ́gun Orí ejò ní yoo bá ejò ṣẹ́gun Orí ejò Mo sé ní ìwúre pe orí kálukú wa yoo báwa ṣẹ́gun ọ̀tá gbogboAkò ní di ẹran...

View Article

Asiri àwo kintú,

Asiri ẹ̀tú kintú, Iwọ iwori bógbè IFA, Ki owá bo asiri mi, Iwọ iwori bógbè. Mogbá ládùrá wipè loni ọjọ àbámẹtá asiri gbógbó wa koni tu kotobó lailai,gbogbo abá ti aba da loni yio jẹ mimusẹ, Aṣẹ̀ aṣẹ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

2019 World Ifa/Orisa Pilgrimage In Ekiti And Ife.

I am very certain that Orunmila and other Orisa will be dancing and enjoying with what is happening with Ifa and Orisa Practitioners Community presently. Why? Because, miraculously with their...

View Article


What Odu Ifa says in Osa logbe

Today, Sunday, Ojo Aiku (day of immortality), Ose Ifa, looking at the Odu, “Osa logbe”, what else can we request from Ifa if not longevity because he/she who is endowed with longevity receives...

View Article

Pari Owe Yii

Ohun to wa leyin Ofa!

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

The Fact That Adó Ewi Is The Home Of Òrúnmìlà Is Undisputable.

Although, we all known that Ile-Ife is the cradle of all Yoruba race, and it is a sacred town that all the deities descended to, so any orisa can be celebrated there, but when they lived many years in...

View Article

Ọmọ: Ẹ̀bùn Edùmarè !

Ẹ̀bùn Edùmarè ni ọmọ Ẹ̀rí ìfẹ́ rẹ̀ sí wa ni wọ́n Èdùmàrè à ń bẹ̀ ọ́ Bá wa wo àwọn èwe yè Fi wọ́n fún àwọn tí ń wojú rẹ fún ẹ̀bùn wọn Má ṣe jẹ́ kí wọ́n kú mọ́ àwọn òbí wọn lọ́wọ́ Èyí a wí yìí, kárọ̀...

View Article


Bí ewúrẹ́ bá bojú wo ẹ̀yìn

Á fi èpè fún elépè Mo sé ní ìwúre wípé gbogbo ọ̀tá tí o bá ń robi tàbí sebi sí èmi àti ẹ̀yin lẹ́yìn yoo ma fí orí ara wọn gbe láṣẹ Ọlọ́run Olódùmarè Àsẹ Eu oro para que qualquer inimigo planeje o mal...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ỌYA: The Guardian Of The Realm Between Life And Death

Ọya is one of the very powerful African Goddesses (Orisa). A Warrior-Queen, she is the sister-wife of the God Sango, to whom she gave the energy to produce storms. A lot of Ọya’s power is rooted in...

View Article

Ẹ Káàbọ̀ sí oṣù tuntun

Oṣù Òkúdù á yanjú gbogbo ohun tí ó ń dùn wá lọ́kàn Ẹnikẹ́ni ò sì ní bá wa du’re ayọ̀ wa. @AlamojaYoruba

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live