KṒJṒDÁ: Aseyi Samodun O! (Happy New Year 10,061 !)
KṒJṒDÁ” – ‘Ki ṓjṓ dá: Meaning; May The Day Be Clear or Foreseen; is the name of Yórúbà Calendar. Akù Odùn Tìtún o! Eyìn Omo Yórubà nìlè lókó, léyín ódì!It is 10,061 of the Yoruba Calendar (Kojoda,...
View ArticleGeomancy Is A Form Of Ifa!
**Ifa is not a form of geomancy. The most outrageous and misleading statement about Ifa I yet have heard is that Ifa is part of some Arab culture, and that it is geomancy. There is NO evidence to...
View ArticleIfá naa ki bayi wipe: Osa Alawure (Osa Otura) – Otua Meji
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi ana o, adura wa yio gba, ori buruku koni je tiwa loni o Àse.Mo nfi akoko yi nki gbogbo onisese patapata kaakiri agbaye wipe aku aseyori odun ifá agbaye o...
View ArticleẸ̀yẹ̀lé
Yiyẹ̀ lonyẹ́ ẹ̀yẹ̀lé, Ayé ayẹ̀ wá kàlẹ̀, Rirọ lonrọ àdábà lọrún, Ayé yio rọrún fún wá jẹ̀, Tùtù ni omi àfi owúrọ̀ pònri, Ao ni mo inira layé ti àwá, Alanú kàn toju igba àlànú lọ, Yio wa wari, Mogbà...
View ArticleTàgiiri
Tàgiiri ma yí nìsóAra rẹ lokùn Ara rẹ ní ajé gbe ńso Gbogbo ara tàgiiri fín so ajé Mo wá se ìwúre lo ní wípé ire owó yoo ma wọlé wa wa ooooGbogbo iṣẹ́ tí abá se,owó rẹpẹtẹ ní a o ma rí ní èrè láṣẹ...
View Article#EsuIsNotSatan: The Importance Of Esu Divinity!!!
Esu is a fundamental Orisa and of great importance in Yoruba land. There is no shrine you will get to in Yoruba land where you will not see the image or a representation of Esu. In fact,...
View ArticleNí Ojúmọ́ Ọjọ́ Àbámẹ́ta Tòní – #Kojoda #Yoruba #Orisa
Òsùn gbó ríró, kí o má dubúlẹ̀Òòró gangan laa bósùnÒsùn dé o Alàwòrò Ọlọ́run ọba ma jẹ kí gbogbo wa saarẹ Mo sé ní ìwúre fun orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ ọjọ́ Àbámẹ́ta tòní wípé àìsàn kéré tóbi aráyé kò...
View ArticleOlowo Palace In Ondo State Nigeria: The largest palace in Africa.
• The 1,000-year royal castle sits upon 180 acres, has 1,000 inner rooms, museum, market, others Bamigbola Gbolagunte, Akure Historians have adjudged the palace of the Olowo of Owo in Owo Local...
View ArticleAraba Of Oworo Kindgom Spotted with Yoruba Generalissimo, Aare Ona Kakanfo –...
Commemoration of June 12 1993 Annulled Election organized by Oodua People’s Congress with National Coordinator, Aare Gani Abiodun Adams, Aare Ona Kakanfo of Yoruba land, Araba Agboola Awodiran, Oloye...
View ArticleIfá naa ki bayi wípé..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o Eledumare ninu aanu re yio fi ire gbogbo wa wari loni o Àse.Ifá yi gbawa niyanju wipe ki a bo ifá pelu obi meji ati agbebo adiye, ki a si se akose ifá...
View ArticleOyo Masquerades Defy Olubadan’s Directive
ADEBAYO WAHEED, Oyo masquerades yesterday defied the directive by the Olubadan of Ibadanland, Oba Saliu Adetunji, that only him and the Oyo State governor, Seyi Makinde should play host to the...
View ArticleAlaafin Of Oyo Condemns Installation Of Yoruba Oba In France – SEE HIS REASONS
THE Alaafin of Oyo, Oba Lamidi Olayiwola Adeyemi, has condemned the proposed installation of Yoruba Oba in France, describing it is a desecration of culture, custom and tradition of the Yoruba race....
View ArticleKọ́kọ́rọ́ ayọ̀ mi: Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ !
Máfi le ènìyàn lọ́wọ́ Ènìyàn ò daWọ́n lè sọ́ sómi Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun tòní wípé kọ́kọ́rọ́ ayọ̀ èmi àti ẹ̀yin, Ọlọ́run ọba kò ní fí le ọ̀tá lọ́wọ́ o. Kọ́kọ́rọ́ Ayọ̀ wa kò ní bọ́ só mi. Àsẹ
View ArticleIfá naa ki bayi wípé…
Ifá gba gbogbo akápò re niyanju wípé ki won o rubo nitori ki a baa le ri orí ayé wa, ki a baa le de ile ileri, ifá ni nkan yio soro tabi le die fun awon ti won ba koti ogboin sebo, ifá ni atirise tabi...
View ArticleAyoka: The Daughter Of Iya Oniworobo Omo baba Elemun Ni Sabo
It been a long time coming But still, I ignored all your forming Have been to the moon and backJust to cater for all that you lack Don’t you realize that you’ve been single for a while ?Have been...
View ArticleOdu “Ose di” cast for today’s Ose Ifa,
Looking at the Odu, “Ose di” cast for today’s Ose Ifa, I can boldly say that we possess the treasure of inestimable value. Just listen:- Sarasara ni won ndafa awoWoyowoyo laa dafa ogberiAdifa fun...
View ArticleOdu Ifa,”Irosun Oyeku” Cast Today For Ose Ifa
Looking at Odu Ifa, “Irosun Oyeku” cast today for Ose Ifa, I can advise all Priests and Priestesses to imbibe calmness in their characters so that they can always achieve their desires. Secondly, the...
View ArticleẸyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko
Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa kí...
View ArticleOri mi Apeere
Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si...
View ArticleOgbè Até
Owó òtún mi ni mo fi n gba ire Adífáfún Sará Sará N’ílé olódùmarè la gbé n báwon Lóri orí eni òré òhun tìmùtìmù rere Àtélewó mi òsì Ni mo fi n gba ìfà Adífáfún Sèbí Sèbí N’ílé olódùmare ni a gbe n...
View Article