Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Orí ejò

$
0
0

Bí kò bá sí ọpẹ́lọpẹ́ orí, à bá tí mú ejò digi lóko
Ìtàkùn mà lejò
Kíni yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò ní yoo bá ejò ṣẹ́gun 
Orí ejò

Mo sé ní ìwúre pe orí kálukú wa yoo báwa ṣẹ́gun ọ̀tá gbogbo
Akò ní di ẹran àmúso lọ́wọ́ ọ̀tá ooo

I pray for everyone of us that our head will safe us from any evil and any plans of enemy against us shall be in vain

Eu oro por todos nós que nossa cabeça nos protegerá de qualquer mal e quaisquer planos de inimigos contra nós serão em vão.

Awóyẹmí Ọlọ́run wà 1


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles