Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.

$
0
0

Alàgbà Nathaniel Ognonanaya Ugwu ni ìsèlè ìjàmbá Okò selè sí.
Alàgbà kan ní ìjo Catholic se oríre wípé èmi rè sì wà láyé nípa tí ikú ti fo orí rè kojá nínu ìjàmbá okò tí ó ní. Gégé bí ìròyìn se so, Alàgbà náà a máà jé Rev. Fr. Nathaniel Ogbonanya Ugwu, ni ìjàmbá okò ti selè sí nípà tí ó n lo fún isé tí won n rán.
Alàgbà yí jé Wòólì ti ìjo tuntun ti won sèsè dá sílè, tí a mò sí : St Augustine Catholic Church ní Umuhu, Eha-Amufu, ní ìjoba ìbílè Isi-Uzo ní ìpínlè Enugu.
A ri gbó wípé Alàgbà yí jáde nínú ìjàmbá náà, tí kò sì fara pa rárá. Bí ó ti le je wípé oko náà tàkìtì ní ojú pópó.
Àwòrán nìyí ní ìsàlè.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles