Tonto Dikeh sòrò nípa arákùnrin tí ó n bá àyànfé ìyàwó rè jà níbi ìpéjo àríyà ti Burna Boy.
Gbajúgbajà Òsèré obìnrin tí a mò sí Tonto Dikeh, ti pín èrò rè sí orí èro ayélujára látàrí fídíò tí won pín níbi tí arákùnrin kan ti n bá àyànfé aya rè jà níbi àpéjo àríyá tí Burna Boy se ní àná.
Gégé bí Tonto Dikeh ti sáré sí ìyàwó náà tí arákùnrin náà kò sì dáwó ìjà dúró.
Bàkan náà bí Tonto Dikeh se so, àlè kò gbodò bá oko ìyàwó jà, àti wípé bí ó bá jé òun ni ìsèlè yi selè sí, òun yóò da owó pò pèlú oko òun láti fi ìyà je irú okùnrín béè.
Ó tún so wípé, kò dára kí èèyàn máa bá ìyàwó tí ó yan àlè jà nítorí kò le dí won lékun rè láéláé.
