Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti...
Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar school ní...
View ArticlePriesthood: The Oluwo, Babalawo or Iyanifa and Awo Atemaki!
Let us read an article on PRIESTHOOD 1. Oluwo: This is a man who has studied and practiced Ifa as a priest for many many years and has not only seen Orisa Odu but owns Orisa Odu (Olodu: owner of Odu)...
View ArticleCee-c pèlú Toolz àti Yaw.
Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.
View ArticleDavido ti pín àwòrán tàtúù míràn tí ó yà.
Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se eré pèlú J Cole àti wizkid.
View Articleogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí...
Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .
View ArticleOmokùnrin Ronke Oshodi Oke, Richmond se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè.
Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke. Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè,...
View ArticleToolz pèlú àwon tí won se àseyege ní BBnaija ti odún yí, Miracle, Nina, Cee-c...
Àwon ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Nina, Alex, Cee-c Tobi àti Miracle ni won ti ya àwòrán pèlú asojú beat FM, Toolz lóòní gégé bí won se bèrè ìrìn àjò won léyìn ìgbélé won.
View Article*ORIN ORILE EDE NAIJIRIA NI EDE YORÙBÁ*
ESE KINNI_ Dìde Èyin Ará Waká jé ipe Nàijíríà K’à fife sin ‘lè wá Pel’ókun àt’sígbàgbó Kìse Àwon Àkoni wá, kò máse já s’ásán K’à sin t’òkan tará Ilé t’ómìnira,àt’àláfíà So d’òkan. *ESE KEJI* Olórun...
View ArticleSANGO, kABIYESI O!!! LALU OBA KOSO ORIKI SANGO.
Olúkòso! Atu wón ka níbi wón gbé ‘ndáná iró. A lé Babaláwo máa dúró kó Ifá, À ti lójò àti lérùn, Kò séni tí Sàngó kò lè pa. À f’eni tí kogílá kolù, À f’eni tí Esù ‘nse, Ló máa fé kolù Esù. Ló máa fé...
View ArticleOríkì Òsun
Òsun sègèsé olórìyà iyùn Awede kí ó tó we’mo Òsun eléyinjú àánú Igbómolè obìnrin Òsaàyò m’olè Òmómó t’enu m’olè Ayaba bìnrin òtòrò èfòn n’ílé ìyá olúgbón Won kò gbodò m’awo Ìran Arèsà Won kò gbodò...
View ArticleORÍKÌ OFA
Otunba Ikanni: Iyeru okin olofa mojo, Omo olalomi, omo a basu Jo o ko Omo la a re, bu u re, Okan o gbodo jukan, Bokan bajukan Nile olofa mojo, Ogun Oba ni i kowon ni roro, IJA kan IJA kan, Ti won ja...
View ArticleORIKI ILORIN Ilorin afonja.
ORIKI ILORIN Ilorin afonja enudunjuyo Ilu to jinna s’ina To sunmon alujana bi aresepa Ilu tobi to yen,won o leegun rara Esin l’egungun ile baba won Akewugberu ni won A s’adura gbore Aji fi kalamu da...
View ArticleÀfi kí á ma dúpé.
Àfi kí á ma dúpé . Ìwo tí o wà láyé Tí ò ń jeun àsìkò Tí o tún ń wo aso àsìkò Ó tó kí olúwa rè sopé Olúwa tún wá ba o se é Ó tún fún o n’ílé kó,ó ye kí ó dúpé Ó tún ra okò bògìní tó tún l’óyé nínú o jé...
View ArticleEbo riru in Florida USA 4th May 2018
Eni ba rubo ni Esu ngbe Esu endow those who make offering Esu is not satan Ebo riru in Florida USA 4th May 2018
View ArticleYoruba Esu & European Satan: What a generational Colloquial misconceptions !
Satan is an European language and it’s best interpreted by the same European people. Conceptually, in Yoruba culture, ESU and Satan remains different in meaning and does not mean the same. While Satan...
View ArticleSpirituality Dictionary Definition: See definition of each term that applies...
Below are the definitions of each term that applies to Spirituality Ajaguna – Name for the head of the Astral Mates family. Astral Mates – Heavenly spirits believed to dwell between the heavenly realm...
View ArticlePhotos: Completion of Ifa initiation of Falowo, Fasayo and Fabukunmi
Glory be to Olodumare for the successful completion of Ifa initiation of Falowo, Fasayo and Fabukunmi with Oloye Lanre Okemuyiwa and Iyanifa Oloye Oloye IdiAgba OlaIfa Stewart in Florida USA 3rd May...
View ArticleAalo apamo Toni: Itan aja ati ijapa!
Alo ooooooo, alo oooooooo. Itan aja ati ijapa. Ni ojo kan iyan mu ni ilu kan, ko si onuje, baba agbe kan wa, to je ipe ohun ni kan ni o gbin n kan si oko re. Ti awon ara ilu ma fi n ri onuje je. Ni ojo...
View ArticleWhat will our identity be ?
I wonder what we will be like in the coming years. I hope that more people come to realise the importance of valuing our culture, tradition and spirituality. We should cherish them rather than...
View Article