Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Oríkì Òsun

$
0
0

Òsun sègèsé
olórìyà iyùn
Awede
kí ó tó we’mo
Òsun eléyinjú àánú
Igbómolè obìnrin
Òsaàyò m’olè
Òmómó t’enu m’olè
Ayaba bìnrin òtòrò èfòn n’ílé ìyá olúgbón
Won kò gbodò m’awo
Ìran Arèsà
Won kò gbodò m’orò
Olúwa mi ló m’orò
Lósi m’opa
Òsun ló mo opa tééré
Tí ń pa wón je

Ògbójú olúdò tí ń lu ìpèsè,òsun Awede wemo wá w’emo re fún wa kò.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles