$ 0 0 Ní ìsàlè ni Àwòrán ayeye ojó ìbí Richmond, omokùnrin gbajúgbajà Òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Ibironke Ojo Anthony, tí a mò sí Ronke Oshodi Oke. Omokùnrin tí ó rewà, tí ó se ayeye odún kàrún ojó ìbí rè, ará òré ti péjú sí ìbí ayeye náà.