Arábìnrin tí ó ti ń pa àwon ará ìlú rè ni owó ti bà tí won sì ti fi se èsin...
Gégé bí ìròyìn se so, arábìnrin tí àwòrán rè hàn ní ìsàlè yí tí ó wá láti Amuda Isuochi ní ìpínlè Abia, ni ó ti ń pa àwon èèyàn ìlú rè, ò n lò èro ayélujára tí ó pín àwòrán àti ìtàn yí jé kí ó di mímò...
View ArticleDavido àti òrébìnrin rè tí a mò sí Chioma Alvrid ní Barbados.
Davido àti òrébìnrin rè, Chioma wà ní Barbados báyìí báyìí láti ya àwòrán Orin tuntun tí Davido sèsè ko. Ó ti pín àwòrán òun àti arábìnrin yí ní orí èro ayélujára tí a mò sí instagram tí ó sì ko síbè...
View ArticleArábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí...
Arábìnrin kan tí ó jé omo Liberia ni ó gé nkan omokùnrin òrékùnrin rè tí òrékùnrin rè sì pa á. Èyin òré wa, ejòwó e jé kí á máa fura nítorí a kò mo irú àwon obìnrin tí à n gbé nísinyí. Arábìnrin yí ni...
View ArticleArákùnrin ológun tí ó rewà ti setán láti fé ààyò okàn rè, e wo àwòrán kí ó tó...
“Àkókò ti wá tó báyìí kí arákùnrin yí fi ìyá àti bàbá rè sílè láti gbárùkù ti ìyàwó rè, kí àwon méjèèjì sì di òkan. Láì dóònà p’enu, eni wa, Okeoma Daniel Onyenaturuchi ti setán láti lo ìgbésí ayé...
View ArticleOríkì Ìjẹ̀bú
Oríkì Ìjẹ̀bú Ìjẹ̀bú ọmọ alárè, Ọmọ awujálè, Ọmọ arójò joyè, Ọmọ alágemo Ògún, Ọmọ aladìye ògògòmógà, Ọmọ adìye bàlókùn, Ara òrokùn, Ara ò radìye, Ọmọ ohun ṣéní, òyòyò mayòmo ohun ṣéní, olèpani, ọmọ...
View ArticleThe Devotee Of Ifá Must Be Courageous. – Holy Verse From Odu Ifá: Irete-Ose
Holy Verse From Odu Ifá: Irete-Ose “He is no coward who doesn’t run away at the noise of civil strife. Just as bees fly out of the hive but leave the hive protected. Just as ants guard their hill...
View ArticleEwe ati igi (Ọgẹgẹ́ leaf and tree)
Ewúrẹ́ ile Ẹgẹ́ kii jẹ ki wọn gun igi ọgẹgẹ Àgùntàn ile ẹgẹ kii jẹ ki wọn gun’gi ọgẹgẹ Ewe Ọ̀gẹ̀gẹ́ kii jẹ ki wọn gun Ọgẹgẹ Ọ̀gẹ̀gẹ́ igi agunla o Ọ̀gẹ̀gẹ́ ẹ oo Igi...
View ArticleReekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì...
Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé Ka bíbélì re kí...
View ArticleAwakò kan tí kò fi ara balè ní ojú pópó ti fi okò fó orí omokùnrin kan ni...
Òdókùnrin kan ni ó se àgbákò ikú òjijì ní ojó mélòó séyìn ní ìlú Jatu ní ìpínlè Edo, nígbà tí ó n gbìyànjú láti fònà sí òdì kejì, arákùnrin yí ni okò tí o n sáré fó ní orí tí ó sì pa á lésèkesè. Ìsèlè...
View ArticleORÍLÈ ÈDÈ MI
ORÍLÈ ÈDÈ MI Nàìjíríà ìlú mi pàtàkì Ìlú t’ókún fún ogbón Pèlú òpòlopò àwon òjògbón Ilé ogbón Tí a ti n hun àgbòn ìwà ìbàjé S’ogúndogójì di ààyò àwon òdó Òsèlú di ohun wón k’èyìn sí Egbé òsèlú di ìkan...
View ArticleÌfé Mi (My Love)
Ìfé Mi (My Love) Eni bíi okàn mi Adúmáradán orenté Olólùfé mi àtàtà Ìfé re ní n pa mí bí otí òyìnbó Lá ì gbó ohùn re Mi ò lè sùn mi ò lè wo Léyìn re kò sí e lò míràn Mo wo òtún mo wo òsì Mo wo iwájú mo...
View ArticleOwe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka
http://ooduarere.com/wp-content/uploads/2018/04/VID-20180416-WA0000.mp4
View ArticleOríkì ìbejì
Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà...
View ArticleOwe Toni: Lati owo Jude Chukwuka
http://ooduarere.com/wp-content/uploads/2018/04/Jude-Chukwuka-owe-toni.mp4
View ArticleIfa The Foundation of Yoruba Land
The Yoruba people of South West Nigeria, are one of the largest ethnic group south of the Sahara Desert. In several ways they are one of the most interesting and important people of the continent of...
View ArticleA difa fun Òrúnmìlà lojo ti baba nlo sotu ife…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi opin ose o, bi a se njade lo loni ako ni subu lase Eledumare Àse. Laaro yi mofe fi kayefi kan to sele ni bi ojó mesan seyin ladugbo mi nilu ikorodu se...
View ArticleOmo ìbàdàn
Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro...
View ArticlePhotos: Drums festival was a success for the Nation and Africa as a whole –...
The Governor of Ogun State, Ibikunle Amosun has stated that the just concluded Africa Drums Festival hosted by the state, generated lots of income for the individuals of their state and the government....
View ArticleIlé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .
Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ti ọ̀run àpáàdì lọ...
View Article