$ 0 0 Davido àti òrébìnrin rè, Chioma wà ní Barbados báyìí báyìí láti ya àwòrán Orin tuntun tí Davido sèsè ko. Ó ti pín àwòrán òun àti arábìnrin yí ní orí èro ayélujára tí a mò sí instagram tí ó sì ko síbè pé àsedúró ayérayé.