“Àkókò ti wá tó báyìí kí arákùnrin yí fi ìyá àti bàbá rè sílè láti gbárùkù ti ìyàwó rè, kí àwon méjèèjì sì di òkan.
Láì dóònà p’enu, eni wa, Okeoma Daniel Onyenaturuchi ti setán láti lo ìgbésí ayé rè pèlú egungun ìhà rè.
E wo àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.