Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa
Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko paÌròyìn láti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro gbogbo kii se lori alabahun ni opopona Eko si Ibadan ati Ibadan si Eko. Lati igba ti awon Julius Berger ti bere...
View ArticleÒògùn náà(Chloroquine phosphate) lè ṣiṣẹ́ fún ìtọ́jú àrùn a jà má mààlà...
Òògùn náà(Chloroquine phosphate) lè ṣiṣẹ́ fún ìtọ́jú àrùn a jà má mààlà (Coronavirus ) tó ń tàn káàkiri. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀rọ̀ yìí dà bí ọ̀rọ̀ ìwé mímọ́ tó sọ pé ” òkúta táwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀, ló di...
View ArticleAmotekun Effect Ripples as Igbo Group Gives 90 Days To South East Governors...
The National Working Committee (NWC) of the Igbo National Council (INC), an Igbo socio-cultural group has issued a 90 days ultimatum to the governors of the southeast zone to inaugurate their very own...
View ArticleFake App ?
Ojo Aje is the original and correct translation in Ede wa. See how some idiots are polluting Ede wa.
View ArticleIlé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létí
Ilé-ẹjọ́ fi mílíọ̀nù mẹ́wàá náírà fa APC létíEjo ti ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja da ni ojo ketala, osu yii ni egbe oselu APC ni awon ko fara mo. Eyi ko tii saba waye ri ni orileede yii, ki...
View ArticleOkùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera
Okùnrin ọmọ Italy kan ti kó àrùn Coronavirus wọ Nàìjíríà- Iléeṣẹ́ ètò ìlera Iléeṣẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó ń rí sí ìsàkóso àrùn ti sọ pé àrùn Coronavirus tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ COVID-19 ti tàn dé Nàìjíríà....
View ArticleEl- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùn
El- Rufai bá e̩bí ènìyàn 51 ké̩dùnNnkan buruku sele ni ilu Giwa ati Igali ni oru ojo aiku moju ojo Aje.Awon adihamora ni won tun ya bo awon ilu ati abule ni ipinle Kaduna ti won si bere si pa awon...
View ArticleOmijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́
Omijé bọ́ lójú ù mi nígbà tí mo rí olóògbé Pa Kasumu gbẹ̀yìn.—Olóyè Lere Pàímọ́ Bá a pẹ́ tí tí, bí ẹni rebi,bi èmi sì gùn gùn gùn bí okùn tó gùn,ikú lòpin èèyàn.Ìjọ aláyé ti dáyé, lakásọlérí ti í...
View ArticlePa Kasumu, ó dìgbà kan ná
Kayode Odumosu,papòdà lẹ́ni ọdún mẹ́tàdínláàdọ́rin Gbajúgbajà òṣèré tíátà Kayode Odumosu tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pa Kasumu ti juwọ́ ìgbẹyìn sáyé pé ó dìgbàkan. ”Èèyàn dáadáa ni wọ́n yàtọ̀ sí pé wọ́n...
View ArticleÈnìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun
Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’OgunÌròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku...
View ArticleIku
Ikú, conventionally translated as death, is in fact not “death.” Iku is the vehicle of ÌPAPÒDÀ, or transition to Ọ̀run, the source of all being. We must all make this transition, because AYÉ LỌJÀ,...
View ArticleGanduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè
Ganduje ti rọ Emir ìlúu Kánò, Sanusi Lamido Sanusi lóyè Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù...
View ArticleỌ̀ràn dé! Alárùn coronavirus di méjì ní Nàìjíríà
Lara ayewo ti ijoba apapo ati awon ajo NCDC (Nigeria Centre for Disease Control) n se pelu awon ti won ba arakunrin ara orileede Italy wo baalu ati oko po. Won n se ayewo yii naa pelu awon ti won jo...
View ArticleÀwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé...
View ArticleDo most Nigerians welcome westernization?
There is fear that the unique cultures and traditions of Nigeria would go extinct in no distance time, even sooner than anyone’s imagination. Some call it civilisation, others see it as betrayal,...
View ArticleỌba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá
Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ni ana yii pelu...
View ArticleAdo Bayero di Emir Kano
Adi Bayero di Emir Kano Ìdààmú ilé ọlá kan kìí rọ̀, ko ko ko níí le. Ní báyìí Ìgbìmọ̀ ìsàkóso Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano ti rọ Emir Sanusi lóyè ní ọjọ́ Ajé, ọjọ́ kẹsàn án Oṣù kẹta ọdún 2020. . Ó ti tó ọjọ́...
View ArticleGómìnà Kaduna, El-Rufai fi ipò kejì dá Sanusi lọlá láàrin ọjọ́ méjì
Gómìnà Kaduna, El-Rufai fi ipò kejì dá Sanusi lọlá láàrin ọjọ́ méjì Ọ̀rọ̀ Sanusi ti fẹ́ jọ ẹni a tì sígbó tó bára rẹ̀ lójú ọ̀nà. A pète pèrò ká dọwọ́ ẹ délẹ̀, pípele ló tún ń pele é síi. Emir ìlú Kano...
View ArticleÒhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ
Òhun tí Ọlọ́run ṣe fúnmi ju n tó tọ́ sí mi lọ— Ọbasanjọ Olóyè Ọbasanjọ, gẹ́gẹ́ bí ara ètò fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin rẹ̀ léwájú àwọn èèkàn lọ síbi àpèjẹ pàtàkì kan fún àwọn àlejò gbogbo....
View ArticleFayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin...
View Article