Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀...
Osinbajo wọ́gilé ìrìn-àjò rẹ̀ lẹ́yìn tí ọ̀kan lára ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ kú lọ́nà pápákọ̀ òfurufú Ọ̀kan lára àwọn ẹ̀ṣọ́ ìgbákejì Ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo sàgbákò ikú ójijì nínú ìjàmbá alùpùpù lọ́jọ́ Ẹtì....
View ArticleÀríwá Nàìjíríà, Ẹ Sọ Ẹran Jọ̀bọ̀jọ̀bọ̀ Nù Bí Ẹ Ṣe Yọ Sanusi – Soyinka
Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Soyinka ti bu ẹnu àtẹ́ lu bí Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano, lábẹ́ ìsàkóso Gómìnà Abdullahi Umar Ganduje, lórí bó ṣe rọ Lamido Sanusi lóyè, gẹ́gẹ́ bí Emir ìlú Kano. Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nínú àtẹ̀jáde...
View ArticleÌwà Pẹ̀lẹ́ (Good Character)
Ìwà Pẹ̀lẹ́(Good Character) is ultimately the basis of moral conduct in Yorùbá Culture and a core defining attribute of an Ọmọlúwàbí. Also, One of the basic concepts of Indigenous Tradition, as the...
View ArticleỌ̀nà Jìbìtì
Bi ara ipede Radio Naigeria O.Y.O ni aye atijo, won ni, “Ifunra loogun agba, pasa ko funra, o ja sina, aja ko funra, aja jin, ti onile naa ko ba funra, ole ni yoo ko lo”. Eyi ni o difa fun gbogbo awa...
View ArticleAlárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hàn
Alárùn kòkòrò corona e̩lé̩è̩ké̩ta fara hànÌròyìn láti o̩wó̩ Yínká Àlàbí Arabinrin ti o sese ti ilu London de ni o bere si nii wuko ti o si n se kata. Ni eyi ti o mu ki o fara re sile fun ayewo...
View ArticleIlé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn wọ́gilé ìyọnípò Oshiomole gẹ́gẹ́ bíi alága ẹgbẹ́ òṣèlú...
Ọ̀rọ̀ fini lògbòlògbò yini nù lọ̀rọ̀ ọ Alága gbogbo gbòò ẹgbẹ́ òsèlú APC dà báyìí o, bí Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ìlú Abuja ti ní Adams Oshiomhole sì ni Alága gbogbo gbòò fún ẹgbẹ́ òṣèlú APC. Ìgbìmọ̀...
View ArticleIkú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩
Ikú agbábó̩ò̩lù: LMC fa ìbínú yo̩– Iroyin lati Owo Akinwale Taophic. Latari iku odo agbaboolu, Chineme Martin’s, eni ti o pade iku ojiji ni abala akoko ifigagbaga ose ketalelogun liigi orileede wa...
View ArticleNítorí Àrùn Coronavirus Ìjọba Àpapọ̀ Ní Káwọn Arìnrìnàjò Láti Orílẹ̀èdè...
Ṣé àwọn àgbà ní ogun tí yóó wọlé kóni, ọ̀nà là á ti í pàdé ẹ.Gẹ́gẹ́ bíi ara ètò láti tètè rawọ́ ọwọ́jà àrùn apini ní mímí èémí Coronavirus wọlé, Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti gbẹ́sẹ̀lé ìrìnàjò láti...
View ArticleBuhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn
Buhari bá ìpínlè̩ Eko ké̩dùn – Ìròyìn lati o̩wó̩ Yínká Àlàbí Ojo buruku esu gbomi mu ni ojo isinmi oni je fun awon ara agbegbe Amuwo Odofin ni adugbo FESTAC.Ijamba ina naa bere ni aago mesan-an aaro....
View ArticleỌ̀nà Jìbìtì 2
Ọ̀nà Jìbìtì 2Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko mo won rii, ti won woo...
View ArticlePeter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́
Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ní báyé bá tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wàáhù wọn ní. Èyí ló díá fún bí àwọn tọ́rọ̀ kàn lágboolé òṣèré e tíátà se ń lọgun tantan pé,láyé ọjọ́sí, eré ìtàgé jẹ́ gbajúgbajà láwùjọ àwọn...
View ArticleÈnìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria
Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni NaijiriaÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di...
View ArticleÀwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola
Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà,...
View ArticleE̩ Fi Àdúrà Rànmí Lọ́wọ́, Nítorí Ọmọkùnrin Mi Ti Lùgbàdi Àrùn Coronavirus …...
Ẹ fi àdúrà rànmí lọ́wọ́, nítorí ọmọkùnrin mi ti lùgbàdi àrùn coronavirus … igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ yìí nígbà kan Fẹ́mi Akínṣọlá Àjàkálẹ̀ àrùn kan tí gbogbo àgbáláayé ń kó bẹ́ẹ́rẹ́ fún lásìkò yìí tí kò...
View ArticleÀfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀
Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di...
View ArticleRonaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay
Ronaldinho ń kó̩ is̩é̩ gbé̩nàgbe̩nà nínú è̩wò̩n ní orílèèdè Paraguay Lati owo Akinwale Taophic Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni...
View ArticleManchester United Ti Se Tán Láti Ra Odion Ighalo Pátápátá
Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! Gudugudu meje ati...
View ArticleAriwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!
Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo. Agbẹnusọ Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo, Tee-Leo Ikoro ló fi ọ̀rọ̀ náà léde...
View ArticleSanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko
Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu....
View ArticleOjúmọ́ Kan, Oògùn Kan
Ilu nla bii orileede Naijiria sowon lagbaye. Ko si odun kan tabi osu kan to le lo lofee ki o ma se si ohun kan ti a maa gbe poori enu. Igba miiran, o le je Obasanjo lo maa ko leta si Aare to maa dogun...
View Article