Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe.

Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe. Owó sìnkú àwon agbófinró ti orílè èdè Nìjíríà ti te Arábìnrin tí ó n se ayédèrú mílìkì olópe ní ònà gbòòrò. Nígbà tí ó ní irú opolo láti se èyí, kílódé tí kò...

View Article


Annual Ifa Festival: Save the date!

Please sing along with me as follows:- Mi o fi sawada mo wi o, mi o fi sawada Bi mo t’ayewa onifa ni N o seMi o fi sawada mo wi o This is not a joke, I declare, I am not kidding If I return to this...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

The Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria – Photos

Bellow is the photo of Elemoso Ogun of Ijagbo Land and Oluode Aluwo Of Offa at the Ogun Festival In Omupo, Kwara State, Nigeria. See another photo bellow

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Iba Eleiye

Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni o...

View Article

Ifa-lafinimona: Ifa, the Pathfinder.

Ifalafinimona Ifa is the pathfinder embrace it as you would your belover.

View Article


Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won.

Ìyàlénu àti ohun tó mórí wú lójé nígbá tí tè’gbón tà’búrò yí dì mó ara won. Àwon arewà omodé méjì yí, ni won ti kí a mo rírì ìfé tí èjè máa ni sí ara won. Omokùnrin kan láti orílè èdè United State ní...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó.

Arewà obìnrin kan ni ó gbé o n je omo (oyàn) rè han nínú àwòrán òun àti oko àfésónà kí won tó se ìgbéyàwó. Arábìnrin tí ó jé omo orílè èdè Nìjíríà ní ó fi orí oyàn hàn níbi àwòrán kí ó tó di ojó...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi...

Egbé agbá bóòlú fún orílè èdè Nìjíríà àti ti Cameroon: Ìghàló gégé bíi òdómokùnrin tí ó gbégbá orókè nínú eré bóòlù náà. Omo egbé agbá bóòlù fún orílè èdè Nìjíríà tí na àwon omo egbé agbá bóòlú...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Èèmò lukutu pébé.

Òdókùnrín tí ó n fi èro ayélujára gbáni, tí ó n se Yahoo yahoo, ni owó ti tè níbi tí ó ti n gbé òkú arábìnrin tí ó pa sí hòtélì lo. Owó sìkún àwon agbófinró ti te odókùnrin tí ô n gbìyànjú láti gbé...

View Article


Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́...

View Article

Oríkì Òrìsà

Oríkì Òrìsà is very important in Yoruba. It is the Oríkì that enables us to understand the characteristics and ways of Òrìsà. Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ifa/Orisa books

Ifa/Orisa books at affordable prices (still in stock) Order for yours now!!!! 1. Ifa: Ohun Enu Olodumare Ifa: God’s Sacred Message to Mankind 2. Ifa: Ohun Ijinle Aye Ifa: Philosophy of Life 3. Egbe:...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn...

OAU se ìràntí àwon akoni tí won pàdánù èmí won sí owó àwon omo egbé òkúnkùn ní ogún odún séyìn. Àwon alámòójútó àti akékòó ilé-èkó gíga Obafemi Awolowo University ti ilé- ife, máa péjo sí gbàgede...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

ERÍWO YÀ! ERÍWO YÀ!! ERÍWO YÀ!!!

Gbogbo ẹ̀yin Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀; Ojú rẹ rèé o : Babaláwo Babájídé Ọ̀ṣúnníyì (Olúwo Jọ̀gbọ̀dọ́ Ọ̀rúnmìlà). Ní òní yìí ni ìgbẹ́jọ́ ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà sí ìdí Ifá...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Yemọja: Nike Davies Okundaye is an Orisa

Is it time to pronounce Oyenike an òrìṣà, at the level of Yemọja, Ọ̀ṣun and Mọ́remí, at the level of Ogun Sango and Obatala? Nowadays, when we mention the word òrìṣà, people immediately think of it...

View Article


Ìsèse Holiday (August 20th)

At Oyo state house of assembly complex, Ibadan. The day ìsèse(august 20th) holiday was passed by the members of the house of assembly.

View Article

Ìgbín

Àkòrò ní ìgbín fà gungi Ìgbín kò lọ́wọ́ Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀ Àkòrò ní ìgbín fà gungi Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní...

View Article


What Ifa Says

Ifa said that:-No matter how quiet you are, No matter how easy going you are,No matter the level of your gentility,You will still have enemies.But Olodumare has given us victory over the enemies. The...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

E ku Ose Ifa

Aráká-AjagaAràkà-AjagaAdifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin ÈdúÈnìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè MejiAráká-Oku-AjagaAràkà-Oku-Ajaga Ase Tedumare Ifabukky Care

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

ORI HUUUU !!!!!!

Who is Ori?The inner gulf, a place, where our destiny is created, is a principle that decides about human lives.Ori is the basis of our personality, decides about our good and bad luck, that is why...

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live