Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

Orin isese

Ao bo isese o, ao bo isese olowo o, isese o lao bo o, kawa to borisa o, BABA mi isese, IYA mi isese, lao bo o, kawa to borisa o, ORI mi isese, IKIN mi isese, lao bo o, kawa to borisa ooo.

View Article


Is there a “complete” written copy of the Odu Ifa ?

People often ask me if there is a “complete” written copy of the Odu Ifa. However, within the Odu Ifa it explains that there is no babalawo who knows all of the Odu Ifa because the pages in the Odu Ifa...

View Article


Odún ìsèsi àgbáyé

Ogúnjó osù kejo (20/8) odoodún ni odún ìsèsi màa ń wáyé káàkiri àgbáyé. Ìlú kòòkan ni ó sì máa ń se odún náà sùgbón àwon ìpínlè Kan wà tí won máa ń se é papò bí ìpínlè Osun. Àjòdún odún ìsèsi àgbáyé ti...

View Article

Arákùnrin kan ni ó na ìyàwó rè, tí ó sì ba àwò ara ré je.

Arákùnrin kan ni a gbó wípé ó na ìyàwó rè tí ó sì dá àpá si lára, ládúrú bí won ti se n kó wa ní èkó lórí bí a se le gbé lókoláya tó. Bí ó tilè jé wípé aláse ni oko lórí aya rè ,ìyan kò so wípé kí ó so...

View Article

Oòni ti ìlú ilé-ifè darapò mó àwon mùsùlúmí ilé-ifè láti kírun ní ojó odún...

Gégé bí a se mò wípé àwon omo léyìn músùlùmí sèsè se àsekágbá odún won ní léyìn tí won ti gba ààwè séyìn léyìn bí osù mejì àti òsè mélòó sèyìn. Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti darapò mó àwon músúlúmi...

View Article


Favour Iwueze ti Destined kids ti setán láti se ìyàwó.

Omo kékeré àná náà ti dàgbà, àdúrà wa ni wípé kí olórun má pa omo fún olómo. Favour Iwueze ìkan lára àwon omo kékeré ìgbàyan ti setán láti se ìgbéyàwó, kí ire ayò náà kárí.

View Article

Ènìyàn tí ó n gbé inú èkú láti ojó yìí tí a kò mò tí ó n jé lágbájá, àwòrán è...

Okùnrin kan tí ó n gbé inú èkú fohún bí egúngún tí a mò sí lágbájá ni àwòrán hàn ní ìsàlé yí fún ànfààní àwa tí a kò da mò. Gbajúgbajà olórin a kó ni l’ógbón ni Lágbájá àwòrán rè rèé yìí.

View Article

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan...

Ìròyìn burúkú gbáà ni ó jé nígbà tí a gbó wípé baba omo Bisola tí ó jé òkan lára àwon omo ilé BBNaija télè kú. Ará ilé àti lára àwon tí ó figa gbága ní BBNaija rí ni Bisola Aiyeola jé tí àwon tí ó mò ó...

View Article


Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà .

Sineto Musiliu Obanikoro ti lo kí Oònirìsà . Sineto Musiliu Obanikoro tí ó jé adarí àwon olúdábòòbò ti orílè èdè Nìjíríà télè ti lo kí baba wa Oònirìsà tí a mò si àrólé odùduwà ní ìlú ilé-ifè ní ojó...

View Article


Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn.

Ajimobi àti Yinka Ayefele pàdé níbi ayeye Àádòrún odún (90) ojó-ìbí Olúbàdàn. Ìyàlénu ñlá gbáà ni ayeye Àádòrún ojó-ìbí olúbàdàn ti ilè ìbàdàn tí a mò sí Oba Saliu Akanmu Adetunji ní ojó Àìkú. Gómìnà...

View Article

Arábìnrin tí kò ju omo odún métàdínlógún (23) lo ta omo rè òsé méfà tí ó sí...

Owó àwon agbófinrín ti te arábìnrin kan ní ìpínlè Edo tí ó jé ìyá omo méjì , Miracle Johnson, fún títa omo rè omo òsè méfà tí ó sì di owó náà ra èro ìbánisòrò fún ara rè. Gégé bí ìwé ìròyìn Punch se...

View Article

Akékòó ilé-èkó gíga tí a mò sí Polytechnic ti ìlú Ede ní ìpínlè Osun ni àwon...

Ní àná ni akékòó ilé-èkó ti poly Ede fi okò pa ènìyàn bíi márùn-ún tí àwon omo tí ó sèsè fé wo ilé-èkó náà pélù okò rè. Bí ó tilè jé wípé, àwon ojú tí ó wà níbè náà so wípé ñse ni omokùnrin náà ti mu...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.  Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Orisa names !

If you name is a Yoruba name It is an Orisa name It does not have to include ogun, Sango, Ifa or any other Orisa name to be an Orisa name. Titilope, Moyosore, Adebayo, Wuraola,Abayomi, Babatope,...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Owonrin Meji: Cast for Ose Ifa

Sometimes your gentility is taken for stupidity but you should ignore them as revealed in the Odu, “Owonrin Meji”, cast for Ose Ifa today. O gba mi leti mi o gba o san O se mi ni’gbo mi o fo’hun...

View Article


Top 5 Most Beautiful Yoruba Actresses 2018 (Photos)

Beauty may maintain the attention of the beholder but you will find generally acclaimed standards of beauty. Those who fall in this category look very appealing to everyone. It’s thought that they were...

View Article

Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a...

Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan . Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won,...

View Article


Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC. Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC fún...

View Article

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún. Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí...

View Article

Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin...

Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti wípé àwon ìlú ló ma dìbò fún...

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live