$ 0 0 Okùnrin kan tí ó n gbé inú èkú fohún bí egúngún tí a mò sí lágbájá ni àwòrán hàn ní ìsàlé yí fún ànfààní àwa tí a kò da mò. Gbajúgbajà olórin a kó ni l’ógbón ni Lágbájá àwòrán rè rèé yìí.