Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.
Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé… ” èyin abiyamo mi ò le mú ayo náà móra...
View ArticleÌròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China. 2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé. 3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú...
View ArticlePhotos: Meet the New Aare Agbefaga of Oworonsoki Kingdom
Installation of Oloye Babalorisa Rudolph Eastman from Trinidad and Tobago as “Aare Agbefaga of Oworonsoki Kingdom” at the Palace of Araba of Oworonsoki Kingdom, Lagos on 4th September 2018 with Yeye...
View ArticleIfá – A Computer Programmer’s perspective
Ifá – A Computer Programmer’s perspective… For some of us who earn our daily bread from programming computers, making the connection between Ifá binary notation and programming is a no brainer. We...
View ArticleIfe Mefa: Ife ni orisun awa eda—Ife is the cradle of humanity!
Olu Igbo is just a revisionist. An attention seeker. He must know that divide and conquer tactics are are no longer fashionable. He should refrain from his unsubstantiated rhetorics. Ife ni orisun awa...
View Article‘We Don’t Worship Idols Because There Is One God’ – Ooni Ile Ife
Ooni of Ife, Oba Ogunwusi Adeyeye Enitan has said that Ife sons and daughters are not worshipping idols, by celebrating Olojo festival yearly. He said there is one God, adding that people irrespective...
View ArticleWhat The Abrahamic apologists want us to believe
Telling our stories begins from looking into the doings of our forebears and excavating the knowledge database resulting from the cultural practices of our ancestors. For so long, we have heard about...
View ArticleAyé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron-...
Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà tí ó lo se àbèwò...
View ArticleArákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu. Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu tí ó ti mu. Won ti kìlò...
View ArticleFact of the Century !
‘We must endeavor to study Ifa and start quoting Ifa instead of quoting Shakespeare’ – Omo Oba
View ArticleReekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.
Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára. E wo àwòrán won ní ìsàlè.
View ArticleMiracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán
Miracle Ikechukwu dé ìlú Imo léyìn ìsinmi olójó gbooro, tí ó pín àwòrán . Gbajúgbajà Bbnaija tí a mò sí Miracle tí ó lo fún ìsinmi olójó gbooro ti padà sí orílè èdè Nìjíríà gégé bí ó se kakè sí ìpínlè...
View ArticleOwolabi Awodotun Aworeni omo Àràbà télè, Araba Adisa Aworeni, di Àràbà Àgbáyé.
Gbogbo onísèsi àgbáyé ti darapò láti fi Omo Ekùn je Àràbà káàkiri àgbáyé. Lóòótó òpò ni yóò ma rò wípé báwo ni ó se tún jé wípé omo Àràbà tí ó sísè náà ni ó tún jé, súgbón eni orí dá kò se é fi ara wé...
View ArticleÀwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko...
Àwòrán àwon tokotayà jí ó tó di ojó ìgbéyàwó won; ìyàwó fi èyìn rè han oko láti yè é wó . Ìyàwó tí ó rewà fé kí oko rè mo ohun tí ó n kó owó lé lórí, àti wípé kí ó wo nkan tí yóò tún ma kó oeó lé lórí...
View ArticleChimamanda Adichie se ayeye ojó-ìbí rè nígbà tí ó pé omo odún mókànlélógójì...
Chimamanda Ngozi Adichie ni won bí ní ojó keèdógún osù kesàn-án odún 1977 (15/09/1977), jé olùkòwé ní orílè èdè Nìjíríà, ó n ko ìtàn kékeré àti èyí tí ó pò, ó n ko èyí tí ó jé ìtàn ojú gbangban àti èyí...
View ArticleArákùnrin Oyinbo yí ló fé ìyàwó rè tí ó jé omo Edo, tí won sì se ìgbéyàwó...
Òyìnbó kò mà le mú ojú kúrò lórò lára àwon omoge orílè èdè Nìjíríà rárá, nítorí won mò wípé arewà ni won, won sì mo ìké oko se, bí kò bá jé béè ogún-l’ógbòn àwon òyìnbó ni ó ti fé omo orílè èdè Nìjíríà...
View ArticleAsòfin egbé APC, tí a mò sí Hon. Timothy Owoeye, fi èjè wè ní òrú gànjó.
Owó pálábá Asòfin egbé APC tí ó sì jé gbòógì , tí ó sì jé asojú ilé ìgbìmò asòfin tí Ilésà ní ìpínlè Osun, ni owó bá nígbà tí ó n fi èjè wè ní àrin òru tí ó sì n be àwon ará agbègbè náà kí won má se...
View ArticleIba Gani Adams pàdánù baba rè .
Baba Ààre Ona-kakanfo ti ilè Yorùbá tí a mò sí Iba Gani Adams ti lo. Pa Lamidi Adams tí ó ta téru nípà ní ojó Àbáméta ní ilé ìwòsàn aládáni ní ìpínlè Eko, baba kú ní ìgbà tí won fé pé ogórin odún. Nínú...
View ArticleGbajúgbajà elétíofe, tí a mò sí Linda Ikeji ti bí omo okùnrin làntì lanti
Gbajúgbajà a gbé òrò sórí aféfé ti gbe sí orí èro ayélujára tí a mò sí insitagiramu, láti jé kí gbogbo àgbáyé mò wípé òun ti bímo, nígbà tí ô ya àwòrán n’ílé ìwòsàn, tí ó sì pe omo máà ní Baby J. Ó ko...
View ArticleAkékòó tí ó se dáradára jùlo ní ilé-èkó gíga tí a mò sí ABUAD gba èbùn nlá...
Bí omo eni bá dára kí á wí, Akékòó gboyè ti ìmò tí ó n se ìtòjú ènìyàn tí a mò sí Medical Student, ti gba èbùn pàtàkí tí a mò dí Okò bògìnì àti owó goboi. Esther Azom ni orúko akékòó yí njé, a gbó wípé...
View Article