Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí Nosakhare Ogbemudia àti Ekan Egonmwa yà.
Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó omobìnrin olóògbé Dr Samuel Ogbemudia, Nosakhare. Nosakhare, arewà omo Gómìnà àwon ológun ti ìwò oòrùn télè, olóògbé Dr Samuel Ogbemudi, ti setán láti se ìgbéyàwó pèlú...
View Article” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n...
” Mi ò l’óyún” Tiwa Savage so béè láti dékun ìròyìn tí kò múná dóko tí won n so nípa rè. Ìròyìn tí ó gbòde kan láìpé ni wípé Tiwa Savage ti l’óyún tí Linda Ikeji so súgbón Tiwa Savage ti dékun ìròyìn...
View Articleolópàá kan ní Enugu ti mú àwon òdóbìnrin méjì nígbà tí won n rìn l’ójú ònà...
Gégé bí eni tí ojú rè to se so, tí ó sì gbe sí orí èro ayélujára se so, olópàá kan ní ìpínlè Enugu ni a ti fi èsùn kàn wípé ó mú àwon òdóbìnrin méjì tí won wò aso ìwòkuwò. A gbó wípé ìsèlè yí selè ní...
View ArticleJuliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .
Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù . Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó...
View ArticleIyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.
Ògbó-n-tarìgì òsèré, Iyabo Ojo ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti àwòrán ara rè nígbà tí ó ti pé ogójì odún tán , ó sì tún fi hàn wípé dunú. Òsèré Iyabo Ojo, yó se ayeye ogójì (40) odún...
View ArticleÀwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.
Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won. Eléyìí ma ti è wuni won sì rewà pèlú oyún won papò. Mo ro wípé oyún kìí mú àwon èlòmíràn rewà ni, bí ti àwon eléyìí kó, won Jo...
View ArticleArábìnrin yí se ayeye ojó-ìbí fún omo òdò rè ní àrà òtò.
Èyin obìnrin n’ílé, èèyàn mélòó ni ó le se eléyìí fún omo òdò rè. Omodé yí àti olówó rè rè é nínú àwòrán yí, àná ni ojó ìbí rè. E jòwó obìnrin mélòó ni ó tún le se èyí fún omo òdò rè.
View ArticleMaryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí...
Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni won ti gbé lo sí ilé ejó ....
View ArticleOdóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè...
Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November...
View ArticleOkò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn...
Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu,...
View ArticleJude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí...
Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. “A le fi tipátipá...
View ArticleÈmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó...
Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ko...
View ArticleArábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní òtá tí ó pò...
View ArticleMaggi Anwuli Oputa: Nwa nwanyi nwa nwoke Charly onye bu Onye newulite anu aru...
Maggy Anwuli Oputa bu nne nke umu asaa mana anuaru ya adokachala, O bu onye newulite anuaru. Nna ya Charly Nwoke, Onye bu nna Ogbe, Kere foto Maggy na asomumpi nke ndi newulite anuaru we dee Ihe a:...
View ArticleOritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye...
Oritsefemi àti àwon òré rè ti dòbálè níwájú àwon ebí ìyàwó rè tí a mò sí àna rè níbi ìgbéyàwó náà, ìgbéyàwó náà dára púpò. N se ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó báyìí.
View ArticleBanky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde...
Banky W àti òré tímótímó tí ó rè le lo gba ìyàwó rè ( Adesua Etomi), Tunde Demuren . Banky W àti òré rè tímótímó fún ìgbéyàwó alárédè rè, Tunde Demuren ni won Jo ya àwòrán papò níbi ìgbéyàwó alárinrin...
View ArticleBanky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won.
Banky W àti Adesua Etomi ya àwòrán pèlú àwon òbí won níbi ìgbéyàwó alárédè won. Tokotayà tuntun, Banky W àti Adesua Etomi pèlú ègbón Adesua Etomi okùnrin, ìyá rè àti àwon òbí oko ní apá òtún èyí ma tún...
View ArticleÌsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.
Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò...
View ArticleBanky W àti Adesua Etomi fi enu ko ara won lénu níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè...
” O le wá fi enu ko ìyàwó lénu báyìí” ni ó ma n dùn jù nínú ìgbéyàwó, tí kò bá rí béè Banky W àti Adesua kò bá má se tó báyìí, won ti fi enu ko ara lénu jù tí àwon àlejò fi so wípé ó ti pòjù, tí won fi...
View ArticleÀwòrán ìsìnkú Akékòó jáde ti ilé èkó gíga Nnamdi Azkiwe (UNIZIK) tí ó kú ní...
Olóògbé Arábìnrin Amaka Ezeokoli tí ó kú ní òsè mélòó séyìn léyìn àìsàn péréte , se ni won ti sin-ín ní ojó Àbáméta (Saturday) ní ìlú tí won bi sí ní Ezioko ní ìjoba ìbílè Gúúsù ti Orumba tí ó jé...
View Article