Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Oritsefemi dòbálè ní iwájú àwon àna rè, àwon òbí Nabila Fash níbi ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

$
0
0
Oritsefemi àti àwon òré rè ti dòbálè níwájú àwon ebí ìyàwó rè tí a mò sí àna rè níbi ìgbéyàwó náà, ìgbéyàwó náà dára púpò.
N se ni ó dàbí kí èmi náà lo se ìgbéyàwó báyìí.

Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles