Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Ìsìnkú àwon tí won kú níbi ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo.

$
0
0

Gégé bí Holychidi Ojlkorie, ìgbákejì olùgba oko àti aya n’ímòràn ti ìjoba ní ìpínlè Imo télè, òpò ènìyàn bí ogbòn ni won kú níbi ìjàmbá burúkú tí ó selè láìpé láàrin glokò epo petiróòlù àti okò èrò elérò méjìdínlógún (18) ni won ti sin wón papò.
Ó ko síbè wípé .
” ìsìnkú òpò, ìsìnkú àwon tí wón kú sí inú ìjàmbá okò tí ó selè láìpé ní ìpínlè Imo . Won jóná ju bí ó ti ye lo. Kí olúwa té won sí aféfé rere.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles