Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n...
Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon...
View ArticleOyeku Meji, the Averter of Death !
Oyeku Meji, the Averter of Death, Oyeku Meji, the Averter of Death, Oyeku Meji, the Averter of Death, I call upon you three times. I beg you, Averter of Death, if Death is coming my way, help us to...
View ArticleCheck out what Ifa says on monogamy & polygamy In Òyèké Méjì.
“What does ifa say about monogamy and polygamy? In Òyèké Méjì, Ifa says: Òkan soso poro l’obirin dun mo l’owo oko To bá di meji A di ijogbon Tó bá di meta A di eta-itule To bá di merin Won a di nigbátí...
View ArticleOmokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó mú ayé mi dára…..ìyáre...
View ArticleHow would you React To This supposed ‘IGBAKEJI OOSA’ ?
Yoruba monarch flays worshippers of Sango, other traditional deities The Oluwo of Iwo, Rasheed Akanbi, has criticised worshippers of traditional gods like Sango, saying there was no basis for such. The...
View ArticleTinubu, Modu Sheriff, Ben Bruce níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki.
Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites )...
View ArticleAy Makun àti Aliko Dangote níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki .
Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè. Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….
View ArticleÀwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí tokotayà yí yà.
Gift Clarke, èyí tí a gbó wípé ó fé fé àfésónà rè kí odún yí tó parí, ni ó pín àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó tí ó rewà yí. Oko àti aya sì dàbí egbin…
View ArticleOmoni àti Nnamdi Oboli se ayeye ìrántí odún métàdínlógún (17) ìgbéyàwó won...
Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won. Won sì pín àwòrán tipétipé won…
View ArticleÌlò wèrè aso Okrika (aso tí won ti lò rí).
‘Okrika’ ni ònà tí àwon ènìyàn Nàjíríà n gbà pe aso tí won ti wò rí, tí won sí wo ìlú. Nígbà tí àwon nkan ti sa èyí tí ó dára níbè àwon kan kò ní aso tí won sì n wo àsàkù aso…
View ArticlePatoranking lo kí Timaya pèlú okò rè tuntun tí won n pè ní Porsche.
Gégé bí Timaya se pin sí orí èro ayélujára(Instagram) tí ó sì wípé . ” omo mi ti dé pèlú àrà òtò, gbogbo ìgbà ni ó ma n mú orí mi wú. PATORANKING mo féràn re ….
View ArticleÌyàwó ga oko kúrú.
Àwòrán àwon tokotaya tuntun, kí olórun fún won ní adùn ìgbéyàwó . Èyí ò wa rewà bí…
View ArticleCossy Orjiakor ní ilé-ìwòsàn tí ó fé se isé abe kí ìdí rè le yo.
Cossy Orjiakor tí a mò wípé óní àyà ni a ti gbó tí ó ti kérora nípa ìdí rè tí ó kéré lénu ojó meta yí, sùbón báyìí ó ti lo sí ilé-ìwòsàn láti sisé abe kí ìdí rè le yo…
View ArticleOkanran: What Ifa Says general sense of the healing process
Based on the evidences about the importance of human beings emotional world and psycho biologic communication in the complex process of getting sick and healing, I asked Ifa for clarification about the...
View ArticleJamil Balogun, omo Tiwa Savage yo pèlú àrà òtò nínú àwòrán tí ó yà.
Omokùnrin Tiwa Savage, Tunji ‘Tee Billz Balogun ti è ti rewà jù. Gbajúgbajà olórin Tiwa Savage pín àwòrán omo rè tí ó rewà, Jamil Balogun nàà yo ní àrà òtò nínú aso aláwò pupa tí ó yí orùn ká.
View ArticleGbajúgbajà òsèré, Mercy Aigbe pín ìròyìn ìbànújé.
Òsèré, ìyá, àti oní káràkátà ti pín aí orí èro ayélujára láti polongo wípé bàbá òun ti dágbére f’áyé.
View ArticleOlópàá kan ní orílè èdè Ghana fi pàsán na arábìnrin yí ní ìdí nítorí ó kò...
Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ìdí látàrí ó...
View ArticleÀwon akékòó ilé-èkó gíga Calabar is ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò .
Àwon akékojáde ti ilé-ìwé giga Calabar (UNICAR) se ayeye ìkékojáde won ní àrà òtò. ” kò rorùn béè ni kò lera …ayò ni a ka gbogbo rè sí!!!”òkan nínú won ni ò pín èyí sí orí èro ayélujára (Facebook).
View ArticleAmbode wo okò ojú omi láti rin ìrìn àjò lórí omi .
Dr. Akinwumi Ambode, Gómìnà ìpínlè Èkó se ayeye láti we okò ojú omi tí ó sèsè rà, okò ojú omi náà sì wà fún ìpínlè Èkó, bí ó se so wípé àwon n sisé láti jé kí ìrìnàjò orí omi rorùn fún àwon àkànse isé…
View Article