Bukola Saraki pàdé Akòwé Ìjoba gbogbogbò tuntun Boss Mustapha.
Ààre ilé-ìgbìmò asòfin Bukola Saraki pàdé Akòwé ìjoba gbogbogbò tuntun (SGF)Boss Mustapha.
View ArticleMikel Obi fi àyè sílè bá àwon omo rè obìnrin méjì Ava àti Mia seré.
Olga, ìyàwó ògbóntàrigì agbá bóòlù Mikel Obi, pín àwòrán ara rè nígbà tí ó n bá àwon omo rè seré , tí ó sì n ka ìwé fún won .
View ArticleÀwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíye ti kéde wípé àwon kò se mó.
Àwon omo egbé òkùnkùn Eiye àti Àíyè ti so wípé àwon kò se mó nígbà tí won se ìwóde gbangba ní ìpínlè Èkó.
View ArticleÀwòrán okùnrin kan ní orílè èdè Cameroon tí ó pa àwon omo rè méta.
Yannick Arnauld Engolo láti orílè èdè Cameroon tí ó sì jé ènìyàn Swiss tí ó dá Miscas àti priceless corporation sílè ni a ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó pa àwon omo rè méta. Ó ti è pe akorin Chidinma...
View ArticleÌyà tí òyìnbó fi je ìran Yorùbá kò kéré.
Bí ó bá jé ti erú tí won kó wa ni kì bá da, bí kò se ikú burúkú tí won fi n pa àwon baba nlá wa. Béè won kò dá owó dúró. Kí Elédùmarè gbà wá lówó won.
View ArticleÀwòrán tí ó yanilénu tí Hailey Adeleke yà.
Omobìnrin kejì ti gbajúgbajà olórin ní orílè èdè Nàijíríà , Davido , omo tí kò tíì fi esè kan ilè baba rè rí, ni ó ti n dàgbà sínú ewà , ó ti è ti rewà jù nínú àwòrán tí ìyá rè pín sí orí èro...
View ArticleStephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó...
Stephanie Coker tún yo ní àrà òtò, ó tún yanilénu nínú àwòrán tuntun tí ó sèsè yà. Stephanie Coker ti se ìgbéyàwó láìpé ojó, tí a bá ní p’aró ìgbéyàwó náà ye é…
View ArticleAisha El-Rufai se àgbékalè ètò abéré àjesára àti láti lé ìta lo l’ára omodé.
Gégé bí Gómìnà ìpínlé Kaduna se pin, El Rufai. “Aisha El-Rufai ti se àgbékalè abéré àjesára àti ìpolongo láti lé ìta lo l’ára omodé.
View ArticleDangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná ní ìlú Kano ní Mílíónú...
Dangote fún àwon tí ó fi ara káásá níbi ìjàmbá iná tí ó selè ní ìlú Kano ní Mílíónú lóna èédégbéta náírà(#500,000,000)…
View ArticleE wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè.
E wo ejò tí aládùúgbò mi pa ní ilé àyágbà rè. O jé kó kúrò ní ilé àyágbé yí.
View ArticleÀwòrán ìsìnkú Akékòó bìnrin ti ilé-èkó gíga Auchi poly tí àwon figilanté yin...
Ódigbéré Ooo Uloko Lawretta Apaume . Olóògbé Lawretta ni won pa… Kí olúwa te sí aféfé rere … Kí ó tó di wípé ó kú ó jé Akékòó Banking and Finance HND2(tí ó sèsè kékòó parí) . Olùkó àti Akékòó yóò ma...
View ArticleÀwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti ìyàwó rè Hausa yà.
E gbe yèwò àwòrán tí ó rewà kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ògá olópàá yí àti olorì tí a mò sí Hauwa yà . Won sì se jómírégí.
View ArticlePeter Okoye se ayeye ojó ìbí fún Anita Okoye.
Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr P gbe sí orí èro ayélujára (Instagram) láti se ayeye ojó ìbí ìyàwó èkejì rè . Anita Okoye tí ó lé odún kan ní òní. Ó ko sí ibè wípé “O kú ayeye ojó ìbí re mama...
View ArticleFunke Akindele tún yo ní àrà òtò .
Funke Akindele tí gbogbo ayé mò sí Jennifer tún yo ní àrà òtò níbi àwòrán yí…
View ArticleE wo ojú Davido ní orí ìtàgé nígbà tí obìnrin náà fi ìdí rù ú .
Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò .
View ArticleE wo ojú Davido ní orí ìtàgé nígbà tí obìnrin náà fi ìdí rù ú .
Kí ló n selè báyìí? Se Davido sèsè n bò ni ? Obìnrin ehn ! E wo bí Davido se n wò bí eni tí ó n lo sí àjùlé òrun re . Òrò kan fun un e jò .
View ArticleGómìnà ìpínlè Eko ti sí ojú ère ” ASA AROKOLO” ní ogonlonto ní Ikorodu lánàá.
Ère tí ó bù áyà tí ó fi àsà wa hàn ní Ikorodu ni Gómìnà ìpínlè Èkó ti báwa sí lánàá.
View ArticleÀwòrán bàbá àti àwon omo rè obìnrin méfà.
Àwòrán bàbá kan láti orílè èdè Nàíjíríà pèlú àwon omo rè obìnrin méfà tí ó rewà. Baba tí orí rè wú pín àwòrán àwon omo rè obìnrin méfà. Won rewà gan ni. Nse ni ó dàbi kí èmi náà bí obìnrin.
View ArticleÀwòrán tí Tonto Dikeh àti Halima Abubakar yà tí won sì rewà nínú àwòrán náà.
Òsèrè orí ìtàgé, Tonto Dikeh gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí tí òun àti òré rè tímótímó , òsèré Halima Abubakar yà.
View ArticleNnamdi Mpiti tí ó jé akunjú (make up artist) pín àwòrán yí .
E má jé kí èrù bà wá . Kíkùn lásán ni , àti wípé èjè iró ni ó wà níbè “.
View Article