Olópàá tí ó n sojú àgó olópàá Domping ní orílè èdè Ghana, Ase Emmanuel Osei ni won ti fi èsùn kàn látàrí wípé ó fi pàsán na arábìnrin odún mókàndílógbòn (29) tí a mò sí Sarah Darko ní ìdí látàrí ó kò láti wo inú èwon.
↧