Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

Olobe Lo Loko Soko-Yokoto

Eto Olobe lo loko soko-yokoto ni o gori afefe bayii,,,,,, Adupe lowo olorun fun abo re lori wa, oba ti o pawa mo titi Di ojo oni, a dagbere ni ijejo, atun dupe wipe eledumare ka wa ye loni. Lori eto...

View Article


Odo Iwoyi !

A ki gbogbo wa ku ise oni, a si ki wa ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E dakun e wa nkan fidi le abi ki e fi idi le nkan, ki a le jo gbadun ara wa loni. Eto wa ti ose yi yoo yato...

View Article


Ojuitere !

ojuitere, iba re’oo baba IFAYEMI ELEBUBON, iba re’oo baba PETER IFATOMILOLA, iba re’oo baba, ADEBAYO IFALETI, baba wa AWODIRAN AGBOLA baba ADEGBOYEGA OMO ODO AGBA, awon agba onifa ti won gbo n’ti ifa...

View Article

Iwure Owuro Toni: 17-04-­2016

E MAA WI TELE MI : …… *Adun, ayo, idunnu ni temi titi aye *Ire owo, ire omo, ire aiku ni temi. *Apari inu mi ko ni ba tode mi je. *Orisun ayo mi ko ni gbe. *Ise mi ko ni dojuru. *Eledua tete ran...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arewa Asa Toni: 17-04-2016 Ogbeni/Alaji Taiwo Hassan (Ogogo)

Arewa asa wa toni ni Alhaji Taiwo Hassan, abi won ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji ninu ile won,  Won losi ile-we alakobere...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Arewa Asa Toni

  FEMI ADEBAYO ODUNLADE ADEKOLA   Taloye kogba eni ti o dara ju ninu awon osere meji yii ?

View Article

Those who have EBO as their weapon has it all.

Ebo doesn’t only solve problems, but Ebo get deep to the cause of the tribulation and solve it from the scratch. Ifa is still listening to prayers like old days. Orunmila still bless like he used to....

View Article

Happy Oosala day to people across the globe.

May we have the blessings and goodness of it. Ase Edumare! Olokun asoro dayo, olokun ajeti aye, olokun iserin ade. All these are names of Orunmila. Now the question is. Is Orunmila same as Olokun? Is...

View Article


Ori Apere

Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori gbe mi O!!! Ori Apere He who is faster...

View Article


Eyin tia, e ku isinmi oni!

ARAYE KONI LU FUN WA JO, BATA-OFO, BATA- IBANUJE BATA-WAHALA won o ni bo si enu- onan gbogbo wa, gbogbo eniyan tiko ba yan Eledua l’odi e bami se ase, toripe INU- ALAGBAFO KI LE TITI KO BINU OMI....

View Article

Ojuitere ooooooo!!

mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni si...

View Article

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ekun mi di erin. *Iku aitojo ko ni pa...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?

Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?  

View Article


Olojo Ibi

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale...

View Article

YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ

A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E – Ekun, ose ko ni je tire. F – Funfun aye re ko ni...

View Article


Bobo B lori Eto Gbajumo Osere

View Article

Aderupoko lori Eto Gbajumo Osere

View Article


Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)

E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu...

View Article

Oba Erediauwa Ti Waja

Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de...

View Article

Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !

Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun re orewa? Ara-ile mi ko...

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live