Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

$
0
0

E MAA WI TELE MI :
……
*Ade ogo mi ko ni si danu.
*Aso iyi, aso eye mi ko fa ya.
*Edumare ma je ki n fi ota se ore.
*Oluwa dakun so egan mi dogo.
*Edumare wa so ekun mi di erin.
*Iku aitojo ko ni pa mi(Ase).
……..
‪#‎OLUWURE‬ : Oloye Agbaje Sabitu Ashamu ati Erelu Amope Somoye(Yeye Atayese).


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles