


ni Ilaro ni odun 1959, baba tobi won ibeji ni, baba
tobi baba won ibeji ni, emerin ototo ni won ti bi ibeji
ninu ile won, Won losi ile-we alakobere christ Church School
towa ni Ilaro nipinle ogun, leyin igbayen ni won losi
ilu Eko nibe naa ni wonsiti pari iwe alakobere won,
leyin nani won losi ile-we(technical School) lati lo
ko ise atun okose (Automobile Mechanic) leyin nani
won tesiwaju pelu sise pelu awon ajo olomi ero
(water coperation) tilu eko fun odun metala
(13years) nigbati odi odun 1981 ni won darapo mo
ise ere ori tage opolopo sinima ni wonti bawon kopa
ninu re, opolopo sinima lawon naa siti gbe jade,
beesini opolopo Ami eye ni wonsi tifi dawon lola pelu