Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo...
Honorebu Suleiman A. Kawu ni yii, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ti n fo iganna nigba rogbodiyan to waye nile igbimo asofin ni akoko ti Goodluck Jonathan wa lori oye gege bi Aare ile Nigeria...
View ArticleWon Fi Leta Pe Pasuma Pe Ko Wa Korin Ni Soosi Baba G.O Adegboye
Abi foto Buroda Alabi Pasuma ko ni mo n wo yii ni? Ko ma si eni ti Olorun ko le fi owo to lokan sa o. Burudo Pasuma, Orobokibo Creator, Oga Nla 1, Ijaya of Fuji, Oluwa yoo ma so agbara yin dotun oo.The...
View ArticleAbiyamo Fi Omije Gbe Omo Re Sinu Koto
Ipokipo ti eda ba wa laye, e pe ko maa dupe. Ibikibi ti ori ba da ni si ka fi ope fun Oluwa oba nitori awon kan ko tile ni ida kan ninu ogorun anfaani ti a ni. Ebi n pa awon kan, kosi si ounje fun...
View ArticleIyalenu: Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti B’Haram So Di Alailara, Alaini...
Ibudo awon eniyan ti Boko Haram So di alailara ati alainile lori latari ijamba ati ikolu Boko Haram ni yii ni Maiduguri to wa ni Ipinle Borno.E le biliifu wi pe sobiri ti won fi n re ile ni won fi n...
View ArticleMilionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!
Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu MalaysiaChukwudi la gbo wi pe o tirafu lati ilu re, Owerri, ipinle Imo...
View Article“Oserekurin Ti Mo Fe Lati Je Ete Re Ni…”: Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran...
Ti a ba n so nipa ise tiata ile Naijeria, Bimbo Thomas ti kuro ni ojewewe ti won nawo juwe re. Lara awon fiimu to ti kopa ribiribi ni eleyii ti Funke Akindele gbe jade ti won pe akole re ni OMO...
View ArticleOsise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’...
Owo ti te CHIKA EGWU UDENSI, okan ninu awon osise ile ise oko ofurufu ARIK Airline ni papako ofurufu HEATHROW ti ilu London pelu ogun oloro kokeeni.Ogun oloro ti won ka mo bobo naa lowo ni won ni iye...
View ArticleOko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna
Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke.Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala re...
View ArticleAso Oge Funke Akindele Ta Lenu Yeriyeri: Jenifa Pe Omo odun Mejidinlogoji (38)
Aworan Funke Akindele niyii niluu Oba nibi to ti n yo ayo ojo ibi re to ko laipe yii (August 24). Ka ma paro, Funke Akindele ta lenu! Lati irun ori re de bata to wo sese ni i sana bi ti ina...
View ArticleAwon Foto Lati Ibi Ijamba Oko Ofurufu Awon Omo Ologun Niluu Kaduna
Awon aworan Oko ofurufu Dornier 228 ti awon omo ologun ile Nigeria ti a kede wi pe o jabo loju orun laaro oni ni yii. Awon eniyan meje ti won wa ninu oko ofurufu naa lo parun patapata. The post Awon...
View ArticleOdaju Abiyamo Fi Ina Jo Omobirin Eni Odun Merindinlogun Loju Ara: O Ni Omo...
Omobirin odaran kan ni owo awon olopaa ti te ni agbegbe Ketu niluu Eko pelu bo se fi ero ayoonu iloso jo omo egbon re ti n gbe pelu re, Bimpe Badmus, omo odun merindinlogun, nidi pelu esun wi pe...
View ArticleOriki Ibeji : Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún
Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. ẸdúnjobíỌmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ.Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí...
View ArticleOko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo
Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti awon...
View ArticleIresi Gomina Ayodele Fayose Tun Pada Wo Ipinle Ekiti
Ikere Ektiti ni won ti pin. Atomode atagba, arugbo naa gba ninu iresi Fayose.Ohun ti awon eniyan so nipa re wa nibi: The post Iresi Gomina Ayodele Fayose Tun Pada Wo Ipinle Ekiti appeared first on Ọmọ...
View ArticleOniroyin Meji Ti Wa Ni Kirikiri Bayii: Ise Iroyin Won Lo Ko Ba Won
Alase banki Fidelity ti Nigeria, Ogbeni Nnamdi Okonkwo ni Oniroyin Seun Oloketuyi gbe saye lori ikanni re, www.naijahottestgist.com wi pe oga banki naa feran ko maa se “yodiyodi” fun awon osisebirin...
View ArticleDiepreye Alamieyeseigha, gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, jade laye leni...
Diepreye Alamieyeseigha, to je gomina ipinle Bayelsa nigba kan ri, ti jade laye leni odun mejilelogota (62) lana Satide. Iroyin to te Olayemi Oniroyin lowo fi ye wa wi pe aisan ejeruru lo pa gomina...
View ArticleTi o ba je wi pe emi ni Oliseh, ohun ti maa se ni wi pe…”- Adegboye Onigbinde
Vincent Enyeama ti n mu goli fun egbe agbaboolu Super Eagles ti dagbere fun egbe agbaboolu naa wi pe o digba kan na leyin odun metala to ti n sise sin ilu baba re. Igbese ikede ifeyinti pajawiri...
View ArticleEre Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli
Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun. Nje o le so iye okada ati keke...
View ArticleKayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo
Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo. E le ka ero awon eniyan nipa okunrin yii nibi: The post Kayeefi niluu Eko: omokunrin ti o lese n wa danfo appeared first on Ọmọ Oódua.
View Article#OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ni “olaju.” Kini olaju? Olaju je...
View Article