Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna

$
0
0


Oko ofurufu helicopter eleyii ti awon ologun n lo fun idanileko lo jabo ni ibuba awon omo ologun to wa ni Kaduna leyin iseju mewaa to gbera soke.

Ilu Abuja lagbo wi pe oko ofurufu naa n lo ki lala re to lo soke to pada wale loju kan naa mbe.
Gege bi itopinpin Olayemi Oniroyin, awon eniyan bi meje ti won wa ninu baalu naa la gbo wi pe won parun.

E ku etileko fun akotun iroyin.

Orisun Iwe Iroyin

The post Oko Ofurufu Helicopter Ti Awon Omo Ologun Ti Jalule Ni Ilu Kaduna appeared first on Ọmọ Oódua.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles