Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all 2260 articles
Browse latest View live

Ogulutu Oro Toni – 16.06.2016

$
0
0

‎SI GBOGBO OBINRIN‬
Hummm obinrin sowa nu oni oko(husband) o feran
oun oti gbagbe pe iwa lewa omo eniyan
‪abi‬

Oti gbagbe wipe bi eso oko(farm) ba da ladaju eye
oko lasan ni mo pada mu ru won je.
Wonyi ni awon nkan ti o ma nda ile ru.
1.ejo inu ile ni riro
2.ope didu (appreciation)
3.imura gidi
4 iwa rere ati iwa irele
5.Aforiti
6.egbe kegbe
7.imo Toto
Ati bebelo

‎gbomi Dada‬
Iwo Iyawo ele osun iba dara komu orilo mase mu
ewa losi ile oko tori ohun ti tan lewa sugbon iwa
kole tan lailai kolohun mapada leyin wa MORI LO
MASE MU EWA LO.
IRE OOO
`‎King Ogulutu Oro‎


Awada Kerikeri

$
0
0

Ebi de, ebi mama de ooo nibo wonti nta oka nile yi Ebami wabo wa oo

Ifa naa ki bayi wipe

$
0
0

| |   |
| |   |
| |  | |
| |   |

YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase.
Odu ifa OKANRAN IRORUN lo gate laaro yi, ifa yi fore Omo gidi ati ire irin ajo lo si ilu alawo funfun fun eniti odu ifa yi ba jade si, ifa ni yio bi awon ologo ati olokiki omo ifa ni ki o rubo.
Ifa naa ki bayi wipe: Kasooto kasooto titi ka jaye pe o san ju ka sebita ka wa laye ka lowo lowo bi oloro jingin a difa fun olokun ajaro okoto lojo ti yio fi gbogbo omo re bi funfun, won ni ko karale ebo ni ki o wa se obi meji, eyele funfun balau, pakata ekuru, agba otin ati igba ewe ayajo ifa olokun ajaro okoto kabomora o rubo won si se sise ifa fun, ko pe ko jina olokun ajaro okoto roole omo ni bibi, o wa fi gbogbo omo re bi funfun ninini gbogbo won si yan won si yanju won lokiki olokun wa njo o nyo o nyin awo awo nyin ifa, ifa nyin eledumare oni riru ebo a maa gbeni eru arukesu a maa da ladaju ko pe ko jina ifa wa bami ni jebutu ire nje jebutu ire ni a nba awo lese obarisa.
Eyin eniyan mi, mo gbaladura laaro yi wipe gbogbo omo ti a ba bi ni yio yan ti yio yanju o, awon omo wa yio je ologo ati olokiki Omo, ako ni bawon bi papanlagi omo o, eledumare yio si gbohun awon ti won nfoju ekun nserahun omo, ire oke okun yio si je tiwa o aaaseee. ABORU ABOYE OOO.

 

English Version – Good morning my people, how was your night? Hope it was enjoyed. I wish you all a vibrant Sunday.
It is OKANRAN IROSUN corpus that revealed this morning, ifa foresee blessing of good child/children and travelling to the town of white people for whoever this corpus revealed out for, ifa advised him/her to offer a sacrifice very well.
Hear what the corpus said: To tell the truth and live long is better than to be falsify and been enjoying inside a lot of money it cast divined for olokun ajaro okoto when she would give birth to white children, she was advised to offer sacrifice so that all her children could be prosper and successful in life two kola nuts, white pigeon, ekuru funfun, gin and ifa leaves and she complied, aftermath she gave birth to white children and they all became famous and successful in life, she started dancing and rejoicing praising priest the priests were praising ifa while ifa was praising God.
My people, I pray this morning that all our children will become successful in life, we shall never give birth to mischievous child and all peoples that were looking unto the eyes of God for child will be answered, we shall receive the blessings of abroad

Faniyi David Osagbami

Arewa Toni – Oònirìsà, Àrólé Oòduà!

Kilode ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo?

$
0
0

ojulu ni otito, ao gbo iru eleyi ri a fi d’eru ba
oloro ni sugbon eleyi ko mi ni omi-inu kilo se
alfa abdul-lateef titilope ifa-iwa(itakure) ki lo de ti
iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo? aaaaaaa
olohun-oba aseyi o wu nio ooo amosaaa yoruba
bo won ni eni to gbe(dig) ile lopa oku mo eni
to sunkun ariwo lasan niwon pa. ki eledua
se iku ni isinmi fun abdul lateef titilope ifa-iwa.
hnmmmmm ase owe ni.olohun fi ayepa fun omo-
eniyan toripe a nlo si oyo o koju si oyo atun
bo lati oyo o tun koju si oyo sebi ilu-
gangan ni. iyen nipe orun lati wa orun nan
lao si pada si sunreeoo.

Se Etuntigbo ?

Omo Olojo Ibi toni

$
0
0

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata.
Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Eledua yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Edumare.

Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O.

Foto: Baba ati omo

$
0
0

O wu Olodumare lo da erin ni ola, Olodumare loni ko ri be.


Check out Where The Adire Heritage Festival Is Launching Next

$
0
0

Adire Heritage Festival is on a Whistle Stop Tour of the world! See where it is taking place next after the up and coming sixth August 2016 occasion to be held in London .

 

Adire, our Yoruba indigo colored fabric is an acquired social root and legacy that has been passed from eras, kept up in the present for the advantage of future era amongst the Yoruba individuals of the West African nation Nigeria.

 

Adire legacy celebration is a brand activity of Iroko Award and prestige TV worldwide. These are European based occasion and correspondence organizations which based its enthusiasm for encouraging and advancing the African society, legacy and qualities to the African individuals in Diaspora. The thought behind the celebration is to effectively empower the soul of unity and patriotism even as they showcase the tastefulness of the African craftsmanship and society in their each occasions.

Adire Photo credit : John Gillow

Adire Photo credit : John Gillow

Around the world Adire has be seen in people of different races and color as predominate, it has become the norms, a widely accepted choice of fashion, art, value, craft, and has brought about a huge and globally appreciated legacy of fashion , physical artifacts and intangible attributes which its influence is apparent.

The last Adire Festival held in Austria

In the festival of fashion, in the festival of birthrights, in the commemoration of our heritage, an event which has seen the light of day in the European city of Austria, which attracted Africans and lovers of African fabrics from different walks, lovers of fashion and culture loving men and women; where we told our stories in myths and tales, the women untied their IRO as the men spread their AGBADA as we vibrantly and energetically twist our waist and whine our bodies to the rythms of the talking drum of GANGAN. Where we had a reminder, lecture, an awakening and an expression of the African beauty and perfections, our elegant nature was set loose even as we were lost in awe of the moment and took delight in our highly colorful and dazzlingly designed Adire textiles.

Photo credit: Deola Sagoe, Adire technique on silk fabric

Photo credit: Deola Sagoe, Adire technique on silk fabric

We dazzled in our maxi skirts, our jewelries, we showcased gorgeously both on the runaway and in the festival precessions, Brilliantly done Adire fabrics, manufactured into handbags, shoes, swim wears, interior materials, school bags and countless more. Nigeria is up next.

 

So come one, come all there will be lots of things to do , see and buy – Exhibition, Fashion show, Bazaar, Hair show, Pageants, Concert, Lectures, Awards, Kids play houses etc
Come and patronise African made products as we create awareness for locally made African fabrics and arts, while showcasing the beauty and sustainability in African texiles

If you are an art practitioner, beauty practitioner, fashion designer, carver, dances, singer, Lover of life and nature, BE THERE.

EVENT VENUE

The proposed venue is National Museum Onikan Lagos, there is adequate security and the location is central for attendance.

EVENT DATE
The Adire Heritage Festival is set to hold from the 15th -17th of September, 2016.

See you there.

Photos from the Adire Heritage Festival held in Austria below:

Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!

$
0
0

OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO

cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa

Ogun Lakaaye – Ogun yeeeeeeeeee

$
0
0

Ogun,the brave orisha that work in the day and
night .
Ogun is the orisha that is well-known for his
power of creativity.
The gods of hunters, woodcarvers, blacksmiths,
barbers, mechanics, medicine men and much
more.
Ogun is the Orisa who clears the way of all
Obstacles and opens the way for Prosperity.
The Orisha that made path for all the orishas to
come to earth when the way was blocked.
Oriki:
Ogun lakaye,onijaoole
ejemun Oluwanran
Adigirigiri re ibi Ija
Alaimonkan monkan eniyan ni o pe bi ogun ba
gba ile
oun a si gba oko lo
Ta ni o sai mon pe orisha ti o gba ile, o le gba
oko gba oko gba odo lowo eni.
Ogun ma mon ba n ja, ire ni o da wa fun mi..ase
Ogun yeeeeeeeeee
Ogun is econgnised by many in the world.In
Benin,Ogun is known as Ogu, in Ghana he is
Called Adade Kofi he indeed is respected
throughout the world

Elesin Oyan

$
0
0

Iba Orunmila Bara Agbonniregun;
Elesin Oyan;
Adagbaa Ojomu;
Gbolajoko Omo Ere l’apa;
Baba Okinkin ti n m’eyin erin fo;
Odudu tii du ori emere ti o je ko fo;
Atori eni ti ko sunwon se!
Iba Baba o!

What is Egungun ?

$
0
0

Egungun , in the broadest sense of the word,
refers to all types of Yoruba masquerades or
masked, costumed figures. When used in its
more specific, common sense, ” Egungun ”
refers to the Yoruba masquerades connected
with ancestor reverence, or to the ancestors
themselves as a collective force.

Ojumo Ire

$
0
0

B’ojumo ba mo ..
Ooye a la ‪#‎peregede‬..
A D’ifa fun Peregede tii se yeye ‪#‎Ojumo‬ .
A KU OJUMO
#Ojumo to mowa Lonii.
‪#‎Ojumo_Ire‬ gbogbo ni yoo je funwa lase Oba mi
Oke .

Olojo Ibi Toni

$
0
0

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alfa Ola Akeem Totofun’un ti won je okan pataki ninu ebi Ooduarere.
Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Eledumare e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Eledua yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Edumare.

Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Oodua rere pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O…


Iba Baami Orunmila

Question of the day – Differences & similarities between Awo, Babalawo/Baba awo

$
0
0

General Discussion!!!

What are the differences and similarities between the following:

1. AWO
2. BABALAWO
3. BABA AWO

Let’s discuss and learn!!!

Happy Ose Ifa today to you all –

$
0
0

Orunmila, a tun Ori eni ti o sunwon se
Sugbon eni t’oba gbo’ri e duro ni
Orunmila, he corrects bad head (destiny)
But for only those who offer their head for deliverance.
Happy Ose Ifa today to you all.
Stay blessed.
From Araba of Oworonsoki Kingdom, Lagos Nigeria.

Ewesooo Dede Ewen Goons Mi

Time to return to using Yoruba, Igbo & hausa as official languages – Ifa Dare writes

$
0
0

In a state of 8.081 million people (2013) according to World Bank, Switzerland is a country in Europe with four official languages which includes French, German, Italian and Romansh. If a country of just 8.081 million could have four official languages then why try to massacre the traditions of over 150 million people in Nigeria.

Is it now the right time to stop living in denial and return to the pathway of societal progress ? Ifa Dare has taken to his facebook page to voice out his opinion.

See what he wrote bellow.

‘They want to live in a progressive society; yet, they frown upon their own language, their own epistemology, and their own moral and spiritual philosophies. They are doing every single thing wrong; yet, they wonder why their society is retrogressive.
A people living in their own land but using a foreign language as their medium of communication and operating under foreign epistemology and spiritual philosophy are akin to a MAC computer configured to run under Windows OS with a virus. They would crash just as the MAC computer is expected to crash. NGR crashed, as a country, because the people refused to embrace the fundamentals. Life is simple but obtuse people make it very complicated!!! ‘

Do you agree with Ifa Dare or not? Lets hear what you think in the comment box bellow.

Viewing all 2260 articles
Browse latest View live