Kabiesi re Edua! a se otito ni oro awon agba to sope mejimeji ni Eledua da eniyan. OUN TO BA JO(resemble) OUN LA FI WE ARAWON EPO-EPA JO POSI ELIRI OWO-ALABAUN JO HANHAN-OPE. tani arakunrin-olokada yi jo(resemble)?
Tani arakunrin-olokada yi jo ?
Sun re o: Francis Aiyegbeni alase ‘D’Rovans Hotel’ ni ibadan
ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ti re orun-alakeji sun reeeoooo Francis Aiyegbeni alase D’Rovans Hotel ni ibadan
Iwure Owuro: 08.05.2016
E MAA WI TELE MI :
……..
*Oluwa gba eru iya lori mi.
*Edumare ma se je ki n seru egbe.
*Oluwa taari alaanu si mi.
*Edumare fiso re so mi.
*Oluwa pase irorun sinu aye mi.
*Iku aitojo ko ni pa mi(Ase).
………
E ku ojulona sinima #ORISUN_OLA latowoo King Ogulutu Oro.
……………..
E KU OJULONA # IBILE_FESTIVAL_ SEASON1.
……….
Ilu ibile.
Ijo ibile.
Orin ibile (Ewi, Ijaala, Esa).
Iwosan ibile.
Ounje ibile.
Aso ibile.
# IBILE2016
……..
Lati fi oruko sile ati
fun ekunrere alaye : +2347031174331.
+2347062422360.
Iki’Ni Fun Ayeye Ojo Awon Iya Wa
ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi..
#Orisa bi #IYA o..
Ko si Laye…
……………..
Iya mi..
Abiyamo lojo Ogun le..
Abiyamo Oloja Aran
Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo…
……………………
Ki Emi gbogbo Awon #IYA wa pata o gun..
Ki #Ounje_Omo o ma koro Lenu yin…
Ki e ma fi Aisan pelu Inira Logba..
Ki #Isu_Omo o jinna fun-un yin je Laye…
Eni tiko ni IYA Laye mo,
Ki #OLUWA bawa Te won si Afefe-Rere..
Ogulutu Oro Toni: 08.05.2016
Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin.
# wo
Opolopo ore lo nfara han gegebi ota
Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore…..
# nje
Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku
mo eyiti inu nrun
Oremi oro aiye gba # ogbon, #imo ati # oye oooo.
# ronu soro mi Dada…….IRE OOOOOO
State of Mind…
One of the terracotta dug out from Ita Yemoo at Ile Ife in the 1900s by Leo Frobenius
Aku ojumo lokun !
Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa nfi asikoyi se ni iwure wipe bi aba se jade loo lowuro toni pelu ASE oLODUMARE a o nijade lu iku lowo, a o nigba ipe apuru beeni a o ni gburo okere banu je… Owo a maje fun ori kankan wa… IFA kan so ninu odu mimo e nigba ti OLODUMARE nba ASIWAJUWA ORUNMILA…
Oni… Iwaju iwaju ni opa ebiti un ree si ADIFA FUN OJU NIJO TIN RE ILU OWO (won ni o karan nile EBO ni kose– OJU RUBO)….
Nje eje ki o lowo o lo owo, owo koko lafin wo igi, owo orisa labuu fun afin, lowo lowo lakun owun abeemi. Owo eje ki olo wo o lo. Gbo owun buburu yio ma dowo fun emi ati iwo…. ASE… EJIRE OOoOOoOO
Iwure Owuro: 14-05-2016
E MAA WI TELE MI :
…..
*Fitila ogo mi ko ni ku.
*Aso iponju ko ni se dede orun mi.
*Oluwa ba mi segun ota ile.
*Edumare ba mi segun ota ode.
*Ina omo ko ni jo mi.
*Ina Aya/Oko ko ni jo mi.
*Oluwa mu mi tayo laarin akegbe e mi(Ase).
Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun
Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo
eleyi ti o ku die ko dojubole.
Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo
re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo
sipo. Laipe yi ni edeaiyede bee sile larin awon
ololufe naa ti Afeez owo si ko eru kuro nile fun
iyawo re. sugbon ni bayi, Olorun ti n da si arin awon
ololufe naa ti nkan si ti n pada bo sipo.
Ninu atejise ti Mide fi sita lori eka Intagramm re,
eleyi ti o lo bayi wipe:
“iji naa ti pari!!!… mo dupe lowo Olorun fun
imupadabosipo!!… mo si dupe lowo gbogbo eyin
ololufe ati gbogbo eyin afenifere… Modupe fun adura
yin ati ati iduroti wa… mo dupe lowo yin gidigidi……
@officialafeezowo….. o kii n se oko nikan….. sugbon
Angeli alaabo mi lo je…. o se ti o n wa nibe pelumi ni
gbogbo igba…. titi aye ni emi yio maa ni ife re!!!.
Ibeere Toni: 15.05.2016
Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun
Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira
Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni 500 naira, egbo na o se tomato won ni adugbo tiyin na!
Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Gbolun kan fun baba oni bata yi
Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi
Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…
eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana fe yowo kuro lori subsidy tinubu, atiku abubakar, fashola, pariwo pe ki jonathan mase be nitori awon omo naija majiya, nigbati eto idibo de egbe APC gbagboro kankan pelu ariwo say buhari say baba awa omo naija na ao si fimu finle akon debo wa fun egbe APC niyen laimope ete lama babo nibe, nisin amabere sini ra epo ni N145, ejo igbawo lamaseida nitori inira yii po.
E Ase iwure yi ooo
Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare
Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo
Gbogbo Eyin Abiyamo ao ni bawo bi ibikubi omo ooo.
Fi Ti Okunrin Akonimogba(coach) Egbe Agbabolu Lesesita (Leicester-club) yi se arikogbon
orewa! iwo nan ma ro ararepin, fi ti okunrin
akonimogba(coach) egbe agbabolu lesesita
(Leicester-club) yi se arikogbon, toripe ORI TI YO
DE ADE BOTI WU KORI KONI SE ALAIDE, atipe ILE
ANU OLOHUN KI SU fun idi-eyi maso ireti nu
l’aye BAO KU ISE O TAN
Iwure Owuro: 16.05.2016
E MAA WI TELE MI :
……
*Emi o ni fi aisan logba.
*Iku aitojo ko ni pa mi.
*Aye ko ni ta epo s’aso ala mi.
*Ori olori ko ni ko ere ise mi. *Itansan ogo mi ko niku. *Edumare ba mi so yeye mi di ayeye(Ase).
………..
#OLUWURE : ABILEKO IYABO ADIGUN ONIRUNGBON.
‘Yee! Yee!! Ni gbogbo n ke’
Basẹ ba mumi
Omi a tan ninu asẹ,
Bígèrè ba mumi
Omi a tan ninu ìgèrè,
ko tan ko tan lajá á lami;
Ó tán n bí ò tàn?
A ráta, a rata, ata kan ojú,
ata n tani bi ata.
Ata kuro lorẹẹ o dọta àtàtà.
‘Yee! Yee! yeee!’ ni gbogbo n ke.
Orile yii Dàdán,
Abi ko Dàdán?
”Eniyan to loun o fọ ibajẹ –
aye yii mọ,
Oluwa rẹ o kan Iyọ ninu ìdin”.
Ayo Ab’ara Bintin !
Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun yin wipe Eledua fi Omo Tuntun Jojolo da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Alhaja wa Adetunji Adenike J ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Oodua Rere.
A wa ngba ni adura wipe, a ti mo ibere omo yi, a o ni mo opin re lase Edumare. Aisan ti n se iya omo leyin ibi omo ko ya nile lodo yin ni oruko Oluwa. Gbogbo ohun ti e nilo lati fi to omo yi ti yoo fi je eniyan laye ni Eledua yoo fi s’eke yin.
Ki Olodumare wa wo ola omo tuntun jojolo yi, gbogbo eda ti nwoju Oluwa fun ohun ayo bayi ki oba mi oke wa dawon lohun ni kia lase Edumare.
~Abel Simeon Oluwafemi
Eto Olobe Loloko: Sokoyokoto !
Adupe lowo eledua, oba alaanu, olorun to ohunkohun ko sooro se fun lati se,Adupe lowo olorun ti o tun ka wa ye ni ojo toni, a ki gbogbo wa ku bi oju ojo ti ri oo, nigiriya a kuku de’run fun gbogbo wa lase edumare (amin) Gege bii okan lara awon ateranse ti a ri gba ni ose ti o koja, wipe ki a mu lara ounje ijebu wa si ori eto, tooo a ti se bii e ti wi oo. Loni IKOKORE IJEBU, ni a mu wa, e ma ba mi kalo..
Awon ohun elo ti a o lo fun IKOKORE wa ti oni ree;-
ISU
ATA GIGUN
EPO
ALUBOSA
EDE
EJA
PONMO
EJA PANLA
IYO,
Bi a o ti poo po ti yoo di odindi ree.
IGBESE AKOKO: A o koko be isu wa, a o ge si kekere, a o si rin. (a le fi iyo die si inu isu yen leyin ti a ba rin-in tan, ki a fi poo papo, ti o ba wu wa ni o)
IGBESE KEJI:– Leyin eyi, a o gbe omi die ka ina, a o da ata sii, ti ata yii ba ti n hoo, a o da ede, eja panla gbigbe, eja, ponmo, Maggi ati iyo die a o de pa ki o hoo fun iseju marun.
IGBESE KETA:-leyin eyi, a o wa ma rora da isu wa ti a rin yen si inu ata obe yen, (bi a se da okara tabi egusi sinu epo), a o wa fi epo die sii, e o si de pa, ki o hoo fun iseju mewa tabi jubeelo.
(AKIYESI) :-Leyin ti obe yi ba ti n ho ni ori ina, a le fi sibi obe wa fo Koko isu yen, ti koko yen ba tobi ju ) .Ti o ba ti jina, ti a too wo, ti o si dun, IKOKORE ijebu ti de’le niyen.
Ki a ma jeun lo ni o ku bayi, A le jee pelu eba tutu, aje boko doweke, aje digboluoko,’yemi ara ijebu, ewe sooooo
Too a o ni ri ju bayi lo lori eto olobe loloko sokoyokoto toni, emi omo yin, aburo yin naa ni OMIDAN FALADE OPEYEMI WURAOLA. Aye wa fun Amoran, Afikun, Ayokuro ati ibeere.
Nje a ri eni ti o ni ibeere bii.?
~Falade Opeyemi Cecilia