Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala arun oju patapata. Bi a...
View ArticleYeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro
Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni The post Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro appeared first on Ọmọ Oódua.
View ArticleInu fiimu wo ni aworan yii ti jade?
The post Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade? appeared first on Ọmọ Oódua.
View ArticleE wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji...
View ArticleAbule wo ni sisi yii ti wa na?
Eleyii tun gaju! The post Abule wo ni sisi yii ti wa na? appeared first on Ọmọ Oódua.
View ArticleOtun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye
Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni...
View ArticleSimisola Omoayan: Omidan ti n filu dara
O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun logbon gidi. Eni to ba wu Oluwa Oba ni...
View ArticleIjamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan
Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon darandaran sadeede...
View ArticleWon gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota
Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo...
View Article“Ijoba APC gbodo je ki eto eko ofe rinle de ileewe giga”– Atiku
Igbakeji Aare ile Naijiria nigba kan ri, Alaaji Atiku Abubakar ti ro ijoba to wa lode yii, eleyii to wa lowo egbe oselu APC, lati je ki eto eko ofe ti won se ileri re kari gbogbo eka ikekoo patapata,...
View Article“Idagbasoke awon akonimoogba gbodo je koko fun NFF” – Amodu
Shuaibu Amodu, okan lara awon igbimo oludari ajo NFF ti so wi pe ona kan pataki lati se igbelaruge fun ere boolu alafesegba abele ni nipa sise eto idagbasoke fun awon akonimoogba ere boolu ile...
View ArticleAwon akekoo LASU yari, won ni awon alase n ko leta si yanponyanrin
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Awon omo egbe akekoo Ifafiti tilu Eko, Lagos State University Students Union (LASUSU) ti bere si ni fariga pelu ifehonuhan latari bi awon alase ileewe naa se fi owo kun owo...
View ArticleSaraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja
Aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki, gba Basketmouth lalejo ninu ile re to wa niluu Abuja The post Saraki gba Basketmouth lalejo niluu Abuja appeared first on Ọmọ Oódua.
View ArticleBaalu Aare Buhar ti bale niluu Iran
Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye. The post Baalu Aare...
View ArticleEmir tilu Kano se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram
Emir tilu Kano, Muhammadu Sanusi II, se abewo si awon to farapa ninu ijamba Boko Haram to waye niluu Kano nibi ti aimoye awon eniyan ti ku. The post Emir tilu Kano se abewo si awon to farapa ninu...
View Article“Iyawo mi n yale, o tun bimo ale fun mi”: Alabi yari ni kootu Ikorodu
Orisun Ogbeni Alabi Rasheed, eni odun mejidinlaadota (48) ti gbe iyawo re, Sherifat, lo si ile ejo lati tu yigi igbeyawo odun mewaa to wa laaarin won ka lOjobo ose to koja yii. Gege bi alaye Alabi ni...
View ArticleDele Momodu se afihan Madueke nigba keji
Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti...
View ArticleOfin mokanla to le mu awo ara dabi omo tuntun jojolo
Orisun 1 E yee sa ara yin sinu oorun koja bo ti ye lo. Paapa julo, e sora fun awon oorun lati bi ago mewaa aaro si ago meji osan. Orisii oorun yii a maa mu ki awo eniyan o sa. 2. E ri wi pe e n se...
View ArticleTinuola Oyindamola pegede!
Oni ni ojo-ibi Omidan Tinuola Oyindamola, okan ninu awon ti won karoyin wa lojoojumo. Adura wa ni wi pe ke e dagba ninu ogbon, ola ati alaafia. The post Tinuola Oyindamola pegede! appeared first on...
View ArticleIyawo Buhari lo ki Tinubu laafin re
Titi aye ni olowo yoo ma sore olowo. Gbajumo yoo ma sore gbajumo nigba ti awon olosi naa yoo ma ba ara won se ninu asosiesan awon mekunnu. Aisha Buhari, aya aare ile Naijiria ti lo ki Oloye agba egbe...
View Article