Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji

$
0
0

Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se afihan Madueke leekansii. Ekunrere iroyin nipa obirin naa kosi ni pe jade ninu iwe iroyin re.

The post Dele Momodu se afihan Madueke nigba keji appeared first on Ọmọ Oódua.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles