KÍ LÓ BÀJẸ́ LÉDÈ WA
Ẹ jẹ́ kí a tibi pẹlẹbẹ mú ọ̀lẹ̀lẹ̀ jẹ. N jẹ́ fífi gẹ̀ẹ́sì kọ́ni lédè Yorùbá le múni yege dáada nínú ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá bí? Gẹ́gẹ́ bíi òwe gẹ̀ẹ́sì kan tí ó wí...
View ArticleAlex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22).
Alex Asogwa di onílè púpò ní Omo odún méjìlélógún (22). Ará ilé Big Brother Naija télè tí a mò sí Alex Asogwa tí ó sèsè towó bo ìwé pèlú ilé-isé tí ó n ta ilè tí ó tún ń ta Ilé, ilé-isé real estate and...
View ArticleBí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun.
Bí ò bá dùn yóò pé, bí ó bá pé yó dùn; Òònirìsà fé ìyàwó tuntun. Sùúrù tí ó lójó ni Omo Ogunwusi fi se, Aláse èkejì Òrìsà so Naomi Oluwaseyi Silekunola di Olorì láàfin rè. Èyin omo odùduwà e kú orí re....
View ArticleIyawo Elese Oosun: The new Olori wasn’t stepping on blood !
Iyawo Elese Oosun. Please lets ask from those who are knowledgeable instead of guessing, if anyone is ignorant of Yoruba customs and tradition. There’s no where in Yoruba tradition where the bride is...
View ArticleSun re o: Yeyelufe Of Ijebu-ife
Mr. Anthony Ademolu and Family announce the passing of the esteemed Elder, the YEYELUFE OF IJEBU-IFE….Sunre ooooo, Yeye! “….With heavy heart and gratitude to Almighty God, I announce the passing on to...
View ArticleKò kò, ó gbà láti se ètùtù, Moronke Naomi Oluwaseyi gbà láti se òun tótó gégé...
Bí won se ni kó se é ló se é. Bí ó tilè jé wípé àtúnbí nínú Jésú ni, kò kò láti se àwon ohun tí ó tó gégé bí olorì láàfin Oòni ti ilé-ifè. Àwòrán ibi tí ìyàwó ti n se àwon ètùtú tí ó ye, tí ó sì dá...
View ArticleOònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè.
Oònirìsà sòrò nípa bí àwon èèyàn se n so kiri wípé èjè ni olorì tuntun tè mólè. Oònirìsà ti jé kí á mò wípé yèyélúwà kò te èjè mólè rárá àti wípé Osùn ni Oluwaseyi Moronke, Yèyélúwà tuntun tè mólè kìí...
View ArticleOgbè Ògúndá (Ogbèyọ́nú)
Ifá pé òun yóò ṣe oore òjijì fún ọmọ Ogbèyọ́nú tàbí ẹni yòówù tí a dáfá yìí fún. Ifá pé ìgbàgbọ́ rẹ̀ kò tó nǹkan nínú òun; pé kó lọ ní ìgbàgbọ́ tó jinlẹ̀ síwájú síi nínú òun Ọ̀rúnmìlà. Ifá pé kí ó máa...
View ArticleGbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí...
Gbajúgbajà olórin tí a mò sí Yemi Alade rèdí fún, ìlúmòókà olórin tí a mò sí Flavour. Gégé bí òrò ata díndín tí ó gbòde kan, òrò nípa Tiwa Savage àti Wizkid tí àwon èèyàn n gbà, tí won sì n je lénu,...
View ArticleToke Makinwa nínú aso ìwè nígbà tí ó lo sí èbá òkun ní ìlú Èkó.
Gbajúgbajà ò n lò èro ayélujára tí a mò sí Toke Makinwa tí gbé ògo tí olórun fún hàn, nígbà tí ó gbé àwòrán ìgbà tí ó wo aso ìwè sí orí èro ayélujára tí ó n jé Ínsítágírámù . Àwòrán tí ó gbòde yí ni ó...
View ArticleOro Isiti (sermon): 27th October 2018
My sermon(oro isiti), Saturday 27th October 2018 at our Temple, Indigene Faith of Africa( Ijo Orunmila Ato)Inc was taken from “Ogbe Fun”. Akole:- Aitele ikilo, okanjua ati sisare owo lona eburu ni...
View ArticleOdu, Otua rete
Looking at Odu, Otua rete cast for today’s Ose Ifa, I conclude that fulfilling the obligation is necessary as a way of thanksgiving. Just listen to the sacred message from the Odu as follows:-...
View ArticleThe process of Òrìsà initiation
Òrìsà initiation is a process that opens you up to the power and higher relationship with your guardian Òrìsà and other Òrìsà. Initiation brings new life, get rid of negativities, wealth, children,...
View ArticleDavido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú.
Davido àti Kiss Daniel nínú o okò ojú òfurufú. Gbajúgbajà olórin àti ìlú mòóká olórin tí gbogbo ayé mò sí Wizkid àti Kiss Daniel ya àwòrán papò nínú okò ojú òfurufú aládani. Nse ni ó dàbí eni wípé won...
View ArticleAkékòó okùnrin tí ó ti wà ní ìpelè tí ó parí ní ilé-èkó gíga polytechnic ti...
Arákùnrin kan ni won yìn ìbon fún ní ilé-èkó gíga polytechnic ti ìjoba ní Oko ní ìpínlè Anambra. Gégé bí ìròyìn se so, olóògbé tí gbogbo èèyàn mò sí ‘ De moon’ jé Akékòó féè pari tí ó sì jé wípé odún...
View ArticleKá ṣojú ẹni Ká sẹ́yìn ẹni Orúkọ tí à á pe ìránṣẹ́ (ìbò) .
Òtítọ́ wọn kò sí láyé mọ́ Aṣẹ̀yìn deni wọn kò wọpọ̀ Àbàtà ńlá abojú dẹ̀gun dẹ̀gun Ká ṣojú ẹni Ká ṣẹ̀yìn ẹni Àwọn mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ní ọmọ ìkọ́fa Ilé Àgbọnnìrègún Baba kọ́won ní dídá ọwọ́ Wọ́n mọ̀ ọ́n dá Ifá...
View ArticleÒsèré Yvonne Jegede àti Oko è kí omo tuntun káàbò tí ó tún jé àkóbí won.
Gbajúgbajà Òsèré Yvonne Jegede Fawole àti oko rè dun nú nígbà tí won bí omo tuntun tí ó tún jé Àkóbí won. Bí ó ti lè jé wípé a kò tí mò bóyà ako ni àbí abo sùgbón a mò wípé ó ti bímo. Yvonne tí ó se...
View ArticleOlorì Basirat tí ó pé odún mókàndínlógún ni ojó mélòó séyìn ya àwon àwòrán tí...
Olorì oba àti ìyá ìbejì ni a gbó wípé ó máa n dá oba lóhùn láàfin àti wípé òhun ni ó máa n pèsè gbogbo nkan tí Kábìèsí fé láàfin àti ní orí èro ayélujára. A gbó wípé kò sí ibi náà tí e ó ti ri Aláàfin...
View ArticleOlódùmarè mà tóbi lóba ooo.
Olódùmarè mà tóbi lóba ooo. Kíni olórun olódúmarè kò le se tán, Olódùmarè tó dá ayé òhun òrun tí ó sì so òrò sí órìlè ayé, òrò náà á máa jé Ifá tí ó fi rán òrúnmìlà baba àgbónìrègún. Òdú ìfá ni ó sì n...
View ArticleKÁDÀRÁ Ò GBÓÒGÙN
Adáni wáyé ti dáni sáyé ná. Káwayé máyà tó sayé dàwáàlọ. Òréré layé kò see wò tán. Àyàfi ká gba kádàrá lókù. Kádàrá ò seé kọ̀ láìgbà. Ádíá f’ẹ́ja tó f’ibú...
View Article