È má jé kì olá èro ayélujára tàn yín je- báyìí ni Joke Silva wí.
Nínú ìfòròwánilénuwò nínú ìwé ìròyìn ti Genevieve Nnaji tí won se fún ognóntàrigì òsèré orí ìtàgé tí a mò sí Joke Silva, ni ó ti gba àwon èèyàn ní ìmòràn kí won má se jé kí ohun tí àwon elégbé òhun máa...
View ArticleOro isiti
My divine message (Oro isiti) at our House of Worship, Indigene Faith of Africa (Ijo Orunmila Ato) Inc on Saturday 29th September 2018 was taken from “Ogunda Fun” summarized below :- Akole- Ase ojo ti...
View ArticleIfa – (16 Odu)
Ejiogbe 1 Ifa warn us to be truthful at all time. Be truthful, upright and honest. you may not be rich or have material things like others but you must be truthful and will not end up in disarray....
View ArticleHappy Ose sango!
Igba ara lanbura enikan kinbu sango lerun adifafun olukoso laalu arabambi Omo arigba ota Segun onbelarin ota onfi ojo jumo konminu ajogun. Tani Peri oba to oo Emi oo operire alade..Sango yiobawa Segun...
View ArticleYorùbá dún
Hà à à!! Elédùmàrè ìgbà wo l’ènìyàn yόò to bo nínú hílàhílo òde ayé yìí nà? Ki baálé ilé jáde láti òwúrò kùtùkùtù àná kό sí ma b’ojú wéhìn wo, Ǹjé irú ìwà béè daa?? Àmò sà à!! Èyí tà á se sikù, Ohun...
View ArticleÀnto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè
Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin. Ó ko síbè wípé: ” Ní àgbàlá ejò nlá nígbà tí mo rin ìrìn...
View ArticleStephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin...
Stephanie Hornecker wo aso tí oyàn rè n hàn feere níbè, tí ó sì dàbí egbin nínú è. Arewà télè tí ó tún jé òsèré orí ìtàgé sùgbón tí ó ti di Olùwòsàn báyìí, Regina Askia pín àwòrán tí ó rewà ti omo rè...
View ArticleOgbe Ika: The importance of non-verbal language.
II I I I II I II I Ogbe Ika indicates Ofo Ase expressed externally like light and focused behavior. To state Ogbe Ika is related to the inner Ofo Ase means to explore the fantastic world of unconscious...
View ArticleEjìnrìn Wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀
Ejìnrìn wọ̀jọ ̀wọ̀jọ̀ Awo Ọlọ́wọ̀ ló ṣefá fún Ọlọ́wọ̀ Eléyìí tí yóò roko roko tí yóò gbé kílìṣí tíí ṣe yèyé ajé wálé Ìji lẹ́lẹ́ – Awo Ìji lẹ́lẹ́ Ìji lẹ̀lẹ̀ – Awo Ìji lẹ̀lẹ̀ Ẹ̀fúùfù lẹ̀lẹ̀ ní jági...
View Article20th Century Opon Ifá divination Tray
An early 20th Century Opon Ifá divination tray, from the collection of the Brooklyn Museum An Opon Ifá (known as La Mesa de Ifá in Latin America) is a divination tray used in traditional African and...
View ArticleÒgúndá Ọ̀wọ́nrín (Ògúndẹ̀rín)
Àtẹ́lẹwọ́ mi ọ̀tún ni mo fi kọ́’fá ń dídá Mo mọ Ifá ń dídá A dífá fún Akítán tíí ṣe ọmọ’yè Oníkàá Àtẹ́lẹwọ́ mi òsì ni mo fi kọ́bò ní gbígbà Mo mọ ìbò ni gbígbà Dífá fá fún Aṣọ̀gbà tíí ṣe ọmọ Ẹkùn ni...
View ArticleLinda Ikeji àti omo rè, tí orúko omo náà n jé Jayce Jeremi nínú àwòrán tuntun.
Gbajúgbajà elétíofe tí gbogbo ayé mò sí Linda Ikeji tí ó sèsè bí omo okúnrin rè ní ojó ketàdínlógún osú kesàn-án odún tí a wà yí, pín àwòrán sí orí èro insítágírámù pèlú omo rè, Jayce. Ó ko síbè wípé…...
View ArticleÌyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa...
Ìyá omo keta gbajúgbajà olórin tí a mò sí Wizkid, tí orúko ìyà omo náà a máa jé Jada Pollock pín àwòrán omo rè, Zion. Alámójútó Olórin àgbáyé, Wizkid tí ó padà di ìyá omo rè, Jada Pollock pín àwòrán...
View ArticleBàbá Sàlá òrun rere re o. Gbajúgbajà elérí orí ìtàgé, tí gbogbo èèyàn mò sí...
Tí won bá ni èèyàn apanilérìn ni baba won kò paró rárá, nítorí àwon gangan ni oyè adérìn-ín-p’òsónú ye. Moses Olaiya Adejuwon (M.O.N), lórúko baba súgbón bàbá Sala ti gba orúko lówó won. Àsé kò sí eni...
View ArticleÒkan lára Ilé ìgbé àwon akékòó ti Ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú ilé-ifè tí a mò...
Òkan lára ilé ìgbé àwon Akékòó ti ilé-èkó gíga ifafitì ti Obafemi Awolowo gbiná ní alé àná. Ilé ìgbé yìí a máa jé Alumni hostel, bí ó ti lè je wípé a kò fi tara tara mo bí ó se selè. Gégé bí a se gbó,...
View ArticleIsé kìí pa ni, ayò ní pa omo ènìyàn
Arábìnrin kan ni aso rè fàya ní enu ìdí látàrí àsejú rè nípa ijó tí ó fé kó mólè dáadáa, kí ó tún owó ijó náà mú láti ilè. Nínú fídíò tí a rí wò, tí a ti yo àwòrán arábìnrin yí ni a ti ri wípé ó kúkú...
View ArticleIkún je dòdò ikún n rédìí, Ikún kò mò pé ohun tí ó dùn a máa pa ni.Arábìnrin...
Ìròyìn jé kí á mò wípé arábìnrin yí ya wèrè léyìn tí eni tí ó ti láya nílé ba lájosepò tán. Gégé bí eni tí ó sún mo se so. Ó so wípé ó ti mo omobìnrin yí lára kí ó má bá oko olóko sún kiri, tí ó sì jé...
View ArticleWhat is the Name of your Orisa?
I love all of my Orisha but I’m definitely an Ogun baby
View ArticleOdún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.
Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80). Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón...
View Article