Ìjàmbá okò tírélà tí ó selè tí ó sì se òpò èèyàn lese ní Gombe.
Èyí ni ìsèlè tí ó selè láìpé ní ojó kejìlá osù kokànlá odún yí ní Gombe ní ìpínlè Gombe tí tírélà fà . lóòtó kò sí eni tí ó kú, sùgbón òpò ni ó se Lése gan. A gbàdúrà kí elédùà mú won lára dá.
View ArticleAjá mi , pitbull pa Àntà tí ó n sólé ,obè ti délè oo.
Èrín pa mí, ajá mi, pitbull pa á lónìí , ta ló fé?
View ArticleSandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
View ArticleRegina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
View ArticleÀàre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
View ArticleGómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì...
Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
View ArticleDestiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.
Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.
View ArticleÈre Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.
Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti férè se tán...
View ArticleÒbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won...
Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí mà le Ooo..
View ArticleFayose se ayeye odún ketàdínlógóta (57)ojó ìbí rè pèlú ìsìn ìdúpé ní sóòsì...
Gómìnà ìpínlè Ekiti Fayose se ìsìn ìdúpé ní gbàgede Lady Jibowu ti ilé ìjoba fún ti ayeye odún ketàdínlógóta ojó ìbí rè. Àwòrán ibi tí ó ti n dì mó ìyàwó rè.
View ArticleÀwòrán tí ó yanilénu tí Empress.
Njamah òsèré Nàíjíríà, Empress Njamah tí ó kò láti ní adé orí , látàrí wípé ó ní owó lówó gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà ti ara rè. Òsèré yí dàbí eni tí inú rè n dùn ó sì tún rewà.
View ArticleÒdóbìnrin àtúnbí yí ti sí tàtúù apá rè pèlú irin gbígbóná.
Òdóbìnrin àtúnbí tí ó jé omo orílè èdè Nàíjíríà, ti jó owó rè pèlú irin gbígbóná ní èróngbà láti pa tàtúù owó rè, gégé bí ó se so wípé èsè ni , ó sì le dínà láti wo òrun rere .
View ArticleA ya àwòrán Bola Tinubu àti Osinbajo.
Igbékejì Ààre Osinbajo àti baba ìsàlè egbé APC Bola Tinubu ya àwòrán papò lánàá níbi fífi ìwé l’ólè tí okàn lára àwon agbenuso ilé ìgbìmò so lórí bí Ààre Buhari se n gbógun ti ìwà jegúdújerá.
View ArticleAyé k’áye ni eléyìí Ooo..
Wón so ìran adúláwò dí eranko, kódà isé tí eranko kò le jé ni won n fi won jé . Won n lo ìran adúláwò n’ílò Ku lò.
View ArticleOmo egbé PDP tí ó n lo fún ipò , Obaze ti lo dìbò fún ara rè.
Omo egbé PDP tí ó n lo fún fún ipò níbi ìdìbò Anambra Oseloka Obaze níbi tí ó ti dìbò fún ara rè.
View ArticleE ye àwon egbé ìyàwó Adesua Etomi wò.
Adesua ti se tán láti se tán láti se ìgbéyàwó. Ìgbéyàwó rè ti è ti súmón etílé.
View ArticleÀwon òdó ní Anambra pa màálù láti gbádùn ojó Nsala won nígbà tí won kò sì lo...
Àwon òdó míràn gbádùn Nsala won, gégé bí won se pín sí orí èro ayélujára.
View ArticleGómìnà Obina náà dìbò níbi ìdìbò Anambra.
Gómìnà Anambra Willie Obiano náà dìbò fún ara rè ní Otuocha ward 1 unit 004.
View ArticleNabila Fash pe àwon obìnrin níjà bí won bá le ya àwòrán làì kunjú bí ti tò òun.
Bí Nabila, ìyàwó olórin kan, Oritsefemi se pín àwòrán tí kò ti kunju tí ó so wípé òun yà léyìn ìdárayá ní òwúrò àná.
View Article