Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.

$
0
0

   Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti férè se tán láti sín.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles