Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

Àwòrán : afurasí omo egbé òkùnkùn kan tí a mò sí Baddo ni owó tè ní Ikorodu.

Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Between Alaafin & Elders Of Yoruba Religion Over Oba Ifa Adimula Of S....

Elders of Traditional Religion worshipers under the aegis of the Concerned Committee of Yoruba Traditional Culture and Faith Ambassadors have stood in defence of three Ifa priests accused of...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Trumponium and Putinita?!

View Article

Hundreds of artists mock Trump in Tehran cartoon competition

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè

Àwòrán láti owó omo oòduà rere. Àwòrán láti ìlú olómìnira kan tí a mò sí Ewédú àti ìgbálè (a fé béè, èrín yakata). Ta ló tún n’ìfé àwòrán láti ìjìnlè ìlú yorùba? N’ísàlè ni àwòrán àjò lo sí ìlú Iseyin...

View Article


Olúbàdàn kìlò kí won má se jàgídíjàgan bí odún egúngún se fé bèrè.

Gégé bí odún egúngún odoodún se ma bèrè l’óla, ojó ajé, ní ìlú Ibadan, ní ìpínlè Oyo, Olúbàdàn ti ilè Ibadan, oba Saliu Akanmu Adetunji ti pè fún àláfíà láti òdò àwon eléégún àti àwon tí ó ń tèle tí kò...

View Article

Falz àti 9ice je oúnje alé papò (àwòrán, fídíò).

Falz ti fi èsì àìgbó ra eni ye hàn láàrin òun àti 9ice nígbà tí òpò rò wípé 9ice ni ó ń báwí nígbà tí ó ń gba àwon olórin ní ìmòràn kí won má fi Orin yin àwon gbájúè mó, nígba tí won ń fi òrò wa lénu...

View Article

Annie Idibia da padà fún olùtèlé rè tí ó pè é ní omobìnrin tó “wor wor “.

Annie Idibia fi àwòrán yí sí orí èro ayélujàra rè (instagram) tí ó rò wípé kò rewà  pè é ní omobìnrin tó ” wor wor ” . Ìyá omo méji tí òhun náà sì da padà fun pé :bí ìyá rè…. Continue after the page...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Yakubu Gowon lo kí Shehu Shagari. 

Olórí ìpínlè télè (former head of state) General Yakubu Gowon lo kí Ààre ti télè Shehu Shagari ní ilé rè ní Sokoto. Gómìnà Tambuwal sìn-ín lo pèlú Olórí àlùfáà Ìjo Catholic ti Sokoto,  Bishop Matthew...

View Article


Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon...

Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú...

View Article

Àsírí sèsè tú sí won lówó wípé ilé-isé mi ní iye owó tí ó tó Dólà lónà...

Kokomaster tí a tún mò sí D’banj le sèsè di òsèré tí ó lówó jù ní ilè adúláwò (Africa). Olórin tí ó sì jé baba omo kan sèsè gbe sí orí èro ayélujàra (instagram) rè pé Cream platform tí ó jé ilé-isé rè...

View Article

“To be a great priest in Yorùbá spirituality, you must be truthful and Honest”

S’òtító s’òtító S’òdodo S’òdodo Ení bá s’òtító n’imolè ó gbè Be truthful Be honest Only those who are truthful will be favored by the Imole. You also need to be patient because : Ìrin baba wa, ìrìn Èrà...

View Article

Odu Ifa Ejiogbe: Iwure that can help to gain Wealth, Prosperity, love and favour

In this article i will explain in detail ifa daily or occasional iwure (prayer or spells) that can be use by any body to gain Wealth And Prosperity and love and favour from people in their life...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Eleda, Elemi…

Olodumare is known as Eleda(The creator/maker), Elemi (The Owner of Life) See more bellow.

View Article

Ògbògbó 

To you Erelú, Why haven’t you come with peace? But with pain and tears, But why!why!why! Why did you like disturbing my girls? Why don’t you let them be? Erelú ògbògbó Why did you like coming l’ógbòn...

View Article


Àwon òrìsà tí e kò mò (sùgbón tí ó ye kí á mò) {Some Orisa you probably don’t...

   Òrìsà Bayani.  Òrìsà alágbára yí ni òrìsà omodé tí a bí pèlú dàda . Ó dára kí a ma bo òrìsà yí kí á sì ma bèèrè fún ìdábòbò, kí á b’orí òtá àti gbogbo ire ilé ayé. Gbogbo ènìyàn ni ó le bo òrìsà...

View Article

Ta Ni Elújoba?

Elújoba ni gíwa tí ó kúrò Lóríi oyè gégé bíi alásé oau Láìpé yìí Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba Ìwà rere àti òótó inú tí Baba fi n sisé ló jé...

View Article


Ìbon pa àwon adigunjalè méta tí ìbon bá láti owó àwon òsìsé ìdábòbò (Task...

Òdómokùnrin méta kan ni owó àwon civilian Joint Task Force Nígbà tí won jalè lówó ní Jato Aka ní ìpínlè Benue tí won pa wón ní bíi agogo méjì òwúrò òní (2am). Gégé bí ìròyìn se so, àwon olè náà, ìkan...

View Article

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigerian jollof rice) ti gbé igbáorókè níbi ìdíje...

Ìresì àsèpò Nàìjíríà (Nigeria jollof rice) ti kéde gégé bi ipò àkókó nínú ìdíje àjòdún Washington DC jollof. Ní ojó kejì osù keje odún 2017(july 2, 2017) omidan Atinuke Ogunsalu ti Queensway...

View Article

Ònà tí èèyàn le gbà gbé pèlú onítìjú obìnrin. (Ways To Deal With An...

Tí ènìyàn bá wà lábé òrùlé kan náà, ó ye kí won kókó gbà pé ìwà wa kò le b’ára wa mu. Nígbà kan náà o kò ní láti yí enìkejì padà kí o sì jé oníyè ara re. Kódà bí o bá gbìyànjú tí a kò rí irú rè rí, o...

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live