Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Gáàsì bú gbàmù ní Cross river tí ó sì pa èèyàn méji, tí ó fa ìpalára fún àwon mérin nínú ebí.

$
0
0

Àwon omo ebí mérin ti igbákejì adarí kíko eré ìdárayá ní orílè èdè Nàìjíríà ” Vice President of Sport Association (SWAN), Eddie Bekom tí a gbà sí ilé-ìwòsàn léyìn ìgbà tí gáàsì tí wón fi ń dáná bú gbàmù láti òdò alámúlé gbè won ní Ikom, Ní ìpínlè Cross river.
Bekom, ìyàwó rè àti àwon omo mérin won nígbà tí Ìsèlè náà selè. Won kókó ń tójú won ní ilé-ìwòsàn ní Ikom télè kí ó tó di wípé won gbe lo sí ilé-ìwòsàn ńlá ní Abakaliki fún ìtójú elékèejì.

Ó se ni láànú, ìyàwó Bekom àti ìkan nínú àwon omo rè ti kú látàrí Ìsèlè yí. Ìròyìn so wípé owó tí ó tó mílíònù méwàá (#10 million) ni wón nílò fún ìtójú won. .

Continue bellow for the English translation


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles