Omo Oba Gwamnishu Harrison, tí won jígbé ,ké pé òun ń fi Nàìjíríà sílè
Olùdarí ilé-isé (CEO) ‘Behind Bar Initiative’, èyí tí ó pín àwòrán ara rè ní ibi tí ó gbé ń sunkún lórí èro ayélujàra (facebook). Ti so àsírí èròńgbà rè láti fi orílè èdè Nàìjíríà sílè lo sí ìlú...
View ArticleLaura Ikeji àti Ogbonaya Kanu kí omo tuntun sí inú ìdílé won ní ìlú òyìnbó...
Omo ìyá Linda Ikeji , Laura Ikeji àti oko rè Ogbonna Kanu kí omo tuntun káàbò sí ìdílé won ní ìlú òyìnbó (U. S). Linda Ikeji kéde ewu omo tuntun náà lórí èro ayélujàra (instagram), níbi tí o ti pín...
View ArticleOwó ti te àwon àpapò tí a mò sí Boko Haram tí won ń dógbón se bíi fúlàní...
NAN, Otaru ti ilè Auchi, Alhaji Aliru H. Momoh , ní ìlú Edo, ti kéde ní ojó ajé bí owó se te okòó lé mérin( 24) àwon afurasí Boko Haram tí won ń se bíi fúlàní darandaran ní agbègbè náà tí owó àwon...
View ArticleEwi Toni: Toju Iwa Re Ore Mi
Toju iwa re, ore mi; Ola a ma si lo n’ile eni, Ewa a si ma si l’ara enia, Olowo oni ‘nd’olosi b’o d’ola. Okun l’ola; okun n’igbi oro, Gbogbo won l’o nsi lo n’ile eni; Sugbon iwa ni m’ba ni de sare’e....
View ArticleTonto Dikeh Pèlú Muhammed Lai Nínú Okò Ojú Òfurunfú
Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí...
View ArticleIná gbé arabìnrin kan tí ó jé akékòó ifáfitì ní ìjoba ìpínlè River (River...
Akékòó ifáfitì ní Ìjoba ìpínlè River kan tí a ò tíì mo eye to ó su ú ni Iná gbé ní ojó ìségun (Tuesday) ojó ketàlá osù kefà (June 13). A bá a tí ó subú lulè léègbé kan tí kò jìnà sí ilé-ìwé náà tí won...
View ArticleDo you know why Ose Ifa is very important? (Must Read)
Let me tell you the super story given to me by my father, Oloye Akano Fasina Agboola, late Araba of Lagos. This is repeated for those who have never heard it before. A Babalawo whose nickname is “Ifa a...
View ArticleÀwòrán Kí Ó Tó Di Ojó Ìgbeyàwó Láàrin Eléyàmeyà
Omo Ooduarere tún gbé tuntun dé ooo, àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó láàrin eléyàmeyà. Femi (yorùba) àti Mma rè tí ó ń jé OGECHI láti (River), inú won dùn púpò gan bí won se ya àwòrán papò nínu aso...
View ArticleBómbù Déru Bà Wón Ní Ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond Bank) Ní Ìlú Jos
Bómbù déru bà wón ní ilé-ìfowópamó Diamond (Diamond bank) ní ìlú Jos, Bí won se fura wípé wón ti wà okò kan gúnlè tí irinsé olóró Bómbù sì wà ní inú rè. Gbogbo òsìsé ilé-ìfowópamó Diamond ti eka...
View ArticleFatai Owoseni sàkóso lílo bíbò ní Ikorodu láti owó omo oòduà rere !
Kàyééfi ńlá gbáà ni súnkere fàkere okò tí ó selè ní ìròlé àná ní bóòsì dúró Agric (Agric bus stop), Ikorodu ní ìlú Èkó. Tí ó kan ògá pátápátá ilé-isé olóòpá (commissioner of police) Ògbéni Fatai...
View ArticleNí Iwájú Si : Nípa Ìlànà Oba Ifá Ti Gúúsù America (South America).
Àrídájú ti so wípé… 1. Àwon ènìyàn kan wà tí won ń lo orúko àti ipò Aláàfin láti fi lu àwon tí kò mò nípa Àsà yorùba ní jìbìtì ní ìlú òyìnbó. 2. Àwon babaláwo tí ó wà lábé ilé-ifá Ìjo ifá Àdìmúlà. Wón...
View ArticleOkò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì.
Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò. LRU gbé okò...
View ArticleÌdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó.
Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó wópò tí àwon omo orílè...
View ArticleOko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.
E jò ó Erànmílówó. Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen a kìí sábà ní aáwò kì í sì jowú...
View ArticleOwó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa.
Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. Gégé bí...
View ArticleÒrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan...
Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa...
View ArticleÌkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin...
Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ó se múra...
View ArticleAkékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí...
Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile...
View ArticleÀwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré.
Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for the English Version
View ArticleInú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music...
Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé. Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. Continue...
View Article