Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).

$
0
0

Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ó se múra látòkè délè bí okùnrin, “ó sì ko “a kú ayeye àjòdún baba sí gbogbo àwon ìyá ń dá gbé n’íta”…
Àwòrán míràn léyìn ìjáde

 

Continue after the page break for the English version.


Viewing all articles
Browse latest Browse all 2260

Trending Articles