GBEJÉÉ KIO NIYI
Éni Aye nyé loni, Kio dakun kio se araré jéjé, Éni Igba sii ndun fun, Kio jare Kio fi araré siwon. Ile-aye Kii se Awailo ilu rara. Olódùmarè Nikan ni aremabo. Ômô ti Abi Loni, ti osi di Éni A Njiké,...
View ArticleIwure Owuro – 14.03.2016
*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni di ibanuje. *Odo aye ko ni gbe mi lo....
View ArticleOro Sunuku – Ore Mi, Iran Kefa .
.( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi....
View ArticleEmi Ibinu
Oruko mi ni IBINU, emi ko le fun wara, sugbon mo le da wara nu. Ise ti eniyan ba fi ogun odun ko jo, emi IBINU le fi iseju kan baaje. Sora fun emi IBINU ti o ba fe se ohun rere nile aye. Inu bibi eru...
View ArticleIwure Owuro – 18/03/2016
E MAA WI TELE MI : …… *Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi. *Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi. *Ogun idile ko ni bori mi. *Ki osu yii to pari, maa gbe ohun...
View ArticleLaye Atijo: Opo Sisu (Nje o dara lati maa supo?)
Ni akoko, mo sure fun toko-taya pe iku aitojo ko ni pa gbogbo wa o(ASE EDUMARE). …….. Ni aye atijo, ti oko ba tete ku, ti iyawo re si tun wa loju-opon, won o ba so pe ki aburo oko su u lopo; to ba si...
View ArticleEwi Toni: Atoto arere
Gbogbo omo Yoruba Ki gbogbo eye igbo pa lolo Etu to n numo lowo O ma lee numo Gbogbo Ekulu ko ma lee numo loka Omo Ade ti de to fe korin ogbon Akewi Imoran de to fe farofo sasaro Imoran Ki lo de? To fi...
View Article#Gbagede Asa-19/03/2016
Omo Oduduwa, Olodumare jogun awo to rewa fun wa; awo dudu ni gbogbo aye mo iran wa si, bo sie je wipe alawo pupa die naa nbe ninu-un wa. ……. Ewa n be lara awo dudu, nitori awa gan ni adumaradan; A dudu...
View ArticleEwi Toni – 20.03.2016
Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? A ni ki tie ni awa omo eniyan n ba...
View ArticleIwure Owuro 21/03/2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iyi mi koni faya. *Olorun...
View ArticleTi o ba ni #500, osi fe da ina okele, Bawo Ni wa Sena ?
TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele #antyfolashadealawada
View ArticleCheck out this 9 Great Pieces Of 3D Street Art
Craftsmanship is a stunning thing. It’s lovely and can help us to relax, whether we’re painting it or simply taking a look at it. These days however, people are more into 3D things than they do 2D...
View ArticleNigerian man, Jelili Atiku dresses like a masquerade to have dinner in Israel...
Jelili Atiku, a famous Nigerian multimedia craftsman who is without further ado in Israel, brought about a great deal of blend after he dressed like a masquerade to eat at the African Studies Gallery...
View Article