*Edumare ma fi omo pa mi lekun.
*Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun.
*Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje
*Ogun aye ko ni bori mi.
*Iji aye ko ni ja lu mi.
*Ayo mi ko ni di ibanuje.
*Odo aye ko ni gbe mi lo.
*Ina aye ko ni jo mi.
*Igbesi aye mi ko ni dojuru.
*Orisun ayo mi ko ni gbe.
*Iseda mi ko ni gbabode(Ase).
↧
Iwure Owuro – 14.03.2016
↧