$ 0 0 Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo