Ojopagogo lori eto Gbajumo Osere
Iwure Owuro 27/03/2016
::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::::
E MAA WI TELE MI :
………
*Edumare ma fi omo pa mi lekun.
*Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun.
*Ogun aye koni bori mi.
*Iji aye koni ja lu mi.
*Inira ati idaamu, koni je temi.
*Aye koni so mi mole bi eran iso.
*Omi aye koni gbe mi lo(Ase).
………..
#OLUWURE : Iyalode Olusola Arike Ola
ARASHIN TAYI AKAN BAR ARAHA JAMA’A GAFA BANZA TASAKE DAWOWA
kwanakin baya wani yayi postin din abinnan inaganin kamar karyane amma saina samu birona rubuta atakarda nagwada naga wallahi dagaskene yanzuma dashi nake amfani inada 21360 a MTN account balance dina shi’isa nake yadashi agari domin kowa yaga abin mamaki, ga’abinda yarubuta kamarhaka,
Mtn sun kara rikicewa acikin ‘yan kwanakinnan gasirrin cin banza ta katin mtn wacce zakatara kudi da mb a layinka iya yadda kaso domin dashi nake amfani walhil azim, inhardai layin MTN nedakai to inkatura za’abaka
Idan kayida katin 200 tozaka samu dubu biyar 5000 tareda 500mb sannan za’a baka bunus 1month, idan kayi da 400 ne to zaka samu dubu goma shabiyar15000 dakuma mb 5gb dub da bunus 2month, idankayida katin 750=zakasamu dubu ishirin dabiyar 25,000 zakuma a baka mb 10gb dakuma bunus3month ” sharadi kar ayi amfanida katin 1500 domin bayayi, ga matakanda zakubi(1) anaso kabar kamar naira 5 ko 10 a account balance dinka,inba hakaba massage din bazaijeba (2) siyo katin na200 ko 400 ko 750 (2)saikaje wajan rubuta massage ka rubuta *serial number na jikin katin* lambobin katin *141*Lmdf# saikutura zuwa wannan” code din na mtn =” +7036999646=”bayan kun tura sai kudan jirakadanna ‘yan sakonni to massege zai shigo wayar kamar haka your Lmdf is….misali 1234 to da zarar yashigo saika saka katin ka ta hanyar danna *555*141*lambobin katin*code din Lmdf da aka katuroma ta message#
Nantake zaku shamamaki wallahi zakaga 200=5000+500mb 400=15000 +5gb 750=+25000+10gb
Saiku gaggauta dan abarku abaya kafin sugano sutoshe domin ko cheat ne:
Owe Toni 27/03/2016
OWE TONI
Bi o ti wu ki oju orun funfun to, sanma dudu yo wa
,,…………………,………………………………………….
No matter how bright the sky clouds will exist(challenges aren’t unusuall)
Àsodúnmódún ní í sawo àsodúnmódún..
Àsosùmósù ní í sawo àsosùmósù,
Odún kì í dun ká má rìí ohun àjòdún. Olódùmarè á soore àrí tókasí fún ire láyé e eni iyì Oba Abel Simeon Olúwafémi bí e ti lé ódún kan lónìí.
Àlékún owó,
Àlékún ogbón,
Àlékún ìmò,
Àlékún ìgbéga
Àlékún ohunrere gbogbo ni yóò máa jé tiyín láse Èdùmàrè. Ìgba odún, odún kan ni o.
Idile Alayo: Oro owun si fe toju sumi
A ki gbogbo wa ku jimo oloyin toni a si ki wa ku abo sori eto Idile Alayo ti ose yi, gege bi ise wa atejise kan ti a ri gba lati owo okan lara won ololufe eto yi ni a o maa ka si wa leti loni, ki a jo fi oju sununkun woo, ki a si gba won lamoran bi o ti ye. E gbo bi atejise na ti lo;-
“Olootu mo ki yin pupo o, e dakun olootu oro mi o po rara, emi ati baale mi ni a jo n se fanfa lori oro kan, oro owun si fe toju sumi, ni mo ni ki n fi to awon ojogbon eniyan leti ki won gba mi lamoran.
Eyin ojogbon ati onilakaye eto Idile Alayo e dakun e lami loye o, odun ikerinla ree ti mo ti wa nile oko, omo merin ni emi ati oko mi jo damoran lati bi, sugbon ni bayi Omo marun ni nbe lagbala wa, idi si ni wipe omo merin akoko ti Eledua fi ta wa loore obinrin ni gbogbo won, beeni oko mi nkigbe oun nilo Arole dandan ni, eyi ni o sun wa ni akarun, sugbon se eniyan o kuku gbon ju Aseda lo, iyalenu ni o je fun wa wipe obinrin ni omo ikarun ti a tun bi.
Beeni mo gba oko mi lamoran wipe ko si eni ti Eledua o le fi se arole, a saa ri idile ti okunrin wa toje obinrin ibe ni Eledua nlo fun ogo idile owun sugbon gbogbo atoto arere mi yi eyin eti oko mi ni o nbo si. Beeni oko mi wipe ti oun ko ba bi omo okunrin, oun ko ni dawo omo bibi duro! Koda mo bi oko mi wipe se ti a ba bi omo mewa ti ko si s’okunrin laarin won, se a o tesiwaju na ni? Beeni oko mi daun wipe ti eniyan ko ba de ibi ti nlo kii duro!
Oro yi wa n se mi ni kayefi tori emi o nife si ki eniyan bimo jo bi eku eda, looto oko mi a maa gbiyanju nipa itoju awon omo o koda kii fi oro awon omo re sere rara, sugbon mo ranti wipe maami a ma ki wa nilo lopo igba wipe omo ti obinrin ba le to ni ki o bi nitori ko si eni ti o mo ile ti yoo mo ni ola.
Nibi ti mo ti nparowa fun oko mi ni o ti na aba meji sile wipe kin mu okan ninu e, akoko ni wipe ki ntesiwaju lati maa bimo titi Eledua yoo fi fi omokunrin da wa lola tabi ki nyonda oun lati fe iyawo miran ki n mu okan nibe.
Oro yi wa so si mi lenu koda o bu iyo si tori nko fi iseju kan ninu ojo aye mi gbadura fun ile olorogun, koda mo korira ile olorogun ju nkan miran lo, nitori nko fe ki ohunkohun da isokan ti nbe ninu idile mi ru, nko si fe nkan ti yoo se akoba fun awon omo mi beeni nko fe tesiwaju lati maa bimo jo bi eku eda!
Iyen ni mo se ni ki nfi oro yi lo eyin ojogbon wipe ni ikorita ti mo wa yi ogbon wo ni a da sii, se ki nma bimo lo lati deni iyawo ikeji ni abi ki nyoda oko mi ki o se ife inu re, eyin ojogbon oro ree o, e jowo e la mi loye o!
Hmmmm oro loko-laya afi ka fi senu ka dake o! Ki ni a o ti se eyi si bayi, nje ti arabinrin yi ba ni anfani lati seda omo se ko kuku ni fi gbogbo omo re se okunrin bayi? Beeni o kuku ye oko iyawo pelu, abi nigba ti awon obinrin wonyi ba gba’le oko won lo lojo iwaju ta ni yoo ma ba alagba yi je oruko po? Eyin baba ati iya wa nile oro ree o, ewo ni ki arabinrin yi se gan bayi???
Edurona ibo la nba oro epo lo ni 9ja bai ooooo … ?
Elo leyin nra epo ladugbo yin????
Iwure Owuro 02-04-2016
E MAA WI TELE MI :
…….
*Edumare ma je ki n soore daran.
*Oluwa ma je ki n gbalejo oran.
*Edumare ba mi segun elenini.
*Oluwa ran alaanu si mi.
*Edumare gba mi lowo alaroka.
*Oluwa dakun rojo ibukun sinu ise mi (Ase).
……….
#OLUWURE : Abileko Yemi Owoyomi Oke.
Ounje Emi Fun T’ooro Yii (02-04-2016)
……………………………………………………….
Iwe-Iroyin #AYEKOOTO_MAGAZINE fun T’osu kerin ti jade sita bayii, #Ogorun naira #100 ni beere fun tire lodo #VENDOR nibi-kibi
……………………………………………………………
AMOYE TONII : #ARABINRIN_FOLASHADE_TEMITOPE
…………………………………………………………..
………………………………….
HUN !!!
#Iya to je omo f’ogun #Odun ..
#Osi to ta omo f’ogbon #Osu ..
Bi ko ba pa omo …
A sin leyin re ..
………………..
WOO ORE WA !!!
Bi #Oluko laye je
Bi a ba se gbe ibe si
la see k’ogbon-mogbon
………………..
GBOMI DAADAA ORE WA !!!
#Iriri_aye kan kii ti nii pa
#Ogbon bayii nii mu koni
#Idojukoo re oni kii sopin #Aye
#Isoro oni kii se titi-lai
……………………………..
DAKUN ORE WA !!!
Maa ranti pe Ohun to le nbo waa dero..
#Adura pelu #Igbiyanju leda fi n bori ogun laye..
…………………………….
A KU OJUMO
A Ku Amojuba #Osu_Tuntun (APRIL)
A tun ku Ojo-nla #JIMOH tonii
Opo Oloyin ati Alayo bee la o dijo maa se loke Eepe lase #EDUMARE ..
Iroyin Ere Idaraya Lerefee (02-04-2016)
Ajo to n mojuto #LEAGUE awon obinrin nile wa “NWFL kede ola ojo keji osu kerin gege bi ojo ti idije boolu LEAGUE obinrin fun saa tuntun yoo gberaso kaakiri ile wa.
………..
Emi ati awon agbaboolu mi nlo si orile-ede #JORDAN lati loo gba ife-eye agbaye fun ile wa NIGERIA ni—————— #BALAH_NKIYU lo so bee
…………
#Ajo_FIFA gbegile Agbeyin iko #SUNDERLAND iyen #EMMANUEL_EBUE leyin lati maa kopa lori papa fun odun kan gbako ninu ere boolu latari bi o se ko lati sanwo fun Oniduro re “AGENT”
…………..
O yeki #PAUL_POGBA ju Ogorun-milionu-pohun owo ile-okere ” £100m pounds” lo ti iko #JUVENTUS ba fe taa ————————— #ANDREI_PIRLO lo so bee
……………..
Iko #LIVEROOL si n foju sona lati ra Atama-tase “STRKER” tuntun iyen lati inu idije #GERMAN_BUDISLIGA —————————– #JUDGEN_KLOP (Olukoni #LIVERPOOL ) Lo so bee..
……………..
Iko #BARCELONIA si ni iko to see ni igbekele-julo kaakiri agbaye ———*****————— #HENRY_THIENRY lo so bee…
……………
Gbigba ise lowo #GARRY_NEVIELE gege bi Olukoni #VALENCIA ko bojumu to————————— #SIR_ALEX_FERGUSON lo so bee…
………………
FRANK LAMPARD : O maa nira fun #CONTE ni saa to nbo lati tuko iko egbe-agbaboolu #CHELSEA …
………….
Mo si ni igbagbo kikun pe a si lee gba ife-eye #EPL ni saa yii————————— #ARSENE_WENGER ( Olukoni #ARSENAL ) Lo so bee
Arewa Asa Toni: Adekunle Kosoko (Gold)
Arewa asa toni ni olorin taka sufe (hip hop) ti gbogbo wa mosi ADEKUNLE GOLD, Won je omo bibi ilu Eko ni idile oba kosoko, ti wonsi jade nilewe gbogbo nise (polytechnic) towa nilu Eko enitoje awokose won nidise Orin ni King SUNNY ADE ati EBENEZER OBEY ti wonsi darapo mo egbe akorin nile ijosin won ti wonsi gbe bawo Orin won ajoji jade nigbati won wa ni omo Odun mee-dogun (15years) opolopo amin eye ni wonti fi dawon lola pelu.
Awon Tia N’Ibadan
Ibadan mesi Ogo,
Nile Oluyole,
Ilu Ogunmola,
Olodogbo keri loju ogun,
Ilu Ibikunle alagbala jaya-jaya,
Ilu Ajayi o gbori Efon se filafila.
Ilu Latosa Aare-ona kakanfo,
Ibadan Omo ajoro sun,
Omo a je Igbin yoo,
Fi ikarahun fo ri mu,
Ibadan maja-maja bii tojo kin-in-ni,
Eyi too ja aladuugbo gbogbo logun, Ibadan ki ba ni s’ore ai mu ni lo s’ogun.
Ibadan Kure!
Ibadan beere ki o to wo o,
Ni bi Olè gbe n jare Olohun. B’Ibadan ti n gbonile bee lo n gba Ajoji.
Eleyele lomi ti teru-tomo n mu ni Layipo.
Asejire lomi abumu-buwe nile Ibadan.
A ki waye ka maa larun kan lara, Ija igboro larun Ibadan.
OMO IBADAN KI NI SOO YIN??
SO N SUO SA????
A nfi akoko yi kede fun gbogbo Omo Yoruba Atata ni Ilu Ibadan ati Agbegbe re wipe Ipade egbe Omo Yoruba Atata eka ti ilu Ibadan yoo waye ni ojo abameta ojo ikerindinlogun osu igbe ti a wa yi.
OJO IPADE;-OJO IKERINDINLOGUN OSU IGBE.
IBI IPADE;-ILE ITURA BEMBO
AKOKO IPADE;-AGO MEJI OSAN
A nro gbogbo Omo Yoruba Atata pata ti o wa ni ilu Ibadan ati ayika re lati gbiyanju kopa ninu ipade yi, fun ilosiwaju ati igbasoke egbe Omo Yoruba Atata kari aye.
IJUWE ONA SI IBI IPADE;- Lati Ibikibi ni igboro ibadan, e wo oko ti nlo si APATA, ki e bo sile ni ILE Epo OANDO. Lati ile epo yi, e rin siwaju die, ki e ya si inu oja. Lati inu oja, e o gun Alupupu (Okada) tabi Keke Maruwa ti nlo si ILE ITURA BEMBO. E sokale ni ile itura yi ki e si wole kanle, e ti debi ipade niyi.
Fun alaye lekun rere lori Ijuwe Ona ati nkan miran e pe awon onka ibanisoro wonyi;-
KABIYESI;-08027840877
Alagba SOMADE OLAWALE AJAO;-08033982750, 09091054057.
Adura wa ni wipe Olodumare yoo ba wa di ojo na mu, ohun ti a ko ro ki yoo ba eyi ti a nro je lase Edumare. A ro gbogbo Olugbe ibadan ati agbegbe re ki a tuyaya tuyaya wa sibi ipade yi se gbogbo wa ni a kuku mo wipe ibadan kii gbeyin nibi gbogbo? Sugbon enu lasan ko ni won fi nse o! O di ojo na ojo ire ki a to mo boya oga nibadan looto.
Baami Somade Olawale Ajao o dowo yin o, Iya Adinni mi Alhaja Adetunji Adenike J o dowo yin, Maami Orimadegun Tunmise Iya’badan, eyin da? Oluko mi Olùkó Èdè Yorùbá Arb, e ku igbaradi, Omidan Falade Opeyemi Cecilia e ku imurasile o, maami Alimat Aina Ismail Fasasi o dowo yin, Alagba Adekunle Soliu o dowo eyin agbagba, Alagba Azeez Wasiu Kobewude e ku igbaradi, omobabinrin Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu. E ku igbaradi. Alagba Olanase Hammed Olamilekan e ku imurasile.
Gbogbo Ebi Omo Yoruba Atata nibadan e ku igbaradai ooo
Eba Wa Da Si Oro Yii ooo
Eyin Okurin Se ele gba wipe ki Iyawo yin je oga yin ni ibi ise ?
Ewi Toni – 09-04-2016
Bisu eni ba ta
Ka fowo booje lo to
Agba ofifo ni dun koro koro
Mo ti reru to domo
Mo si ti riwonfa to ko peteesi
Igba o lo bi orere
Owo aago laye
To ba lowaju a tun pada seyin
Igba lonigba n ka
Ile o si meni n teun
Agemo ti n tele yoyooyo
Iku n foga sara rindin
Se opolo ti n janra mole
Nni ‘ku o ni san?
Ore se jeje ile n mi
Boo ba gbagbe
Je n ran o leti
So o ranti Kaaruna olowo aye?
Abi o gbagbe Farao onipo atata
Gbogbo pakaleke e won
Ani gbogbo fufulenge ki lo wa dure le?
Baa ba n fapa ajanaku n sanyan
Baa ba n fitan ogongo joka
Bo ba buse gada to buse gede tan
Dedengbo ni o pada fi gbogbo wa yata
Gbogbo mo le goke mo le so
Gbogbo fufulanga fufulanga
Afemi afemi
Nijo iku ba de laapon a pin
Bi’ya re ba lowo bi olowo aye
Ti Baba n fagbo bolojo moguro
O je ranti pasan bansa laye
Gbogbo gulegule o kojaa saare
Ojo tifa a peran
Topele yoo sebe oyinmolaka
Tomo Awo o ni le gbokele nko?
Se ipa o wa ni pin?
Feso jaye ore
Boo ba lowo lowo
Seranti alaini
Boo ba n gbokele atata meta lojumo
Ranti eni n fagbara kaka jeekan
Se o si wa mo wi pe ilakaka re ko rara
Kadara o ku fagba
Atila o fa girigiri asedanu ofo
Ki lo ha de taa kuku fowo wewo
Ka fese wese
Kaye o le ye mutumuwa
Opo oro o kuku k’agbon
Yooba ni:afefe ni n baa lo
Ka ranti atubotan
N lorin ti mo n diju magbari n ko.
……………
…………….
O to ojo meta taa rira wa,bi o nidii obinrin o ni je
kumolu,Eyi to ba si je kumolu a je wi pe…………
tor e seun eyin omoran ti n moyun igbin E ma
binu si mi. ire o.
Iwure Owuro – 09/04/2016
E MAA WI TELE MI :
……….
*Edumare pase irorun sinu aye mi.
*Oluwa tanmole si ogo aye mi.
*Eni to n se atako ire aye mi, Oluwa f’eje re setutu ola mi.
*Oluwa gbe alaanu dide si mi.
*Pasan ti aye fi n je mi niya, Edumare ba mi dana sun won.
*Oluwa s’ekun mi derin(Ase).
…….
Ogulutu Oro Toni
si gbogbo okunrin
hummmmm moseba gbogbo obinrin ooooooo………eyi ni oruko meta ti OLOHUN so wipe awon OBINRIN nje ti gbogbo OKUNRIN SI GBODO MO,,,
Akoko:AWAWU
Ekeji: ONIGBAGBE ENIYAN
Eketa: ONIFENU
# wo
ore wa majeki ohun ti obinrin re tabi iyawo ile se fun o dun o tori bi ase dawon niyen ooooo
# nje
oranti pe ohun elege lobinrin eni?
# jekinso fun oo
mareti dada kankan lodo awon obinrin tori ONIGBAGBE eda niwon..
#wo
lojo ti won ba se dada sio mofe komope osesi nio tori ONIFENU eda niwon..
# ki
se`jo won o bi ase dawon niyen oo
WONYI NI DIE LARA NKAN ti TOBINRIN NFE
1 MALUWO
2 MAJAGBE MOWON
3MAFI ETO WON DUN WON
Oya efi tiyin naa kun……………………???
What Ifa Says in Ogbe Ate
In Ogbe Ate, Ifa says everybody should do Itefa (Ifa initiation) to know one’s mission on earth, one’s destiny and in order to have all good things of life.
A ki i ji ni kutukutu/ Ka ma modu to dani saye/ Dia fun Olupo Alaelu/ Eyi ti i feyin ti/ To n fekun se-rahun ire gbogbo/ Eyi tile aye ni lara koko bi ota/ Won ni ebo ni ko se/ Ko si lo re e tefa/ O gbebo o rubo/ Ko pe ko jinna/ Ire gbogbo wa yade tuuru tuuru/ Ifa de Alase/ Ope Abise wara,
It is not good for one to start life/ Without knowing the Odu that brought one to the world/ Di-vined for Olupo Alaelu/ Who worried/ And crying for his inability to be successful in life/ Not get-ting all goods of life/ His life was too hard for comfort/ He was advised to offer sacrifice/ And to do Ifa initiation/ He complied/ Before long/ All good things of life became his lots/ Ifa the embodiment of Ase is there/ Ope which predictions must come to pass.
Blessings of Irunmole on all. Baba Olosun.
Lovely Photos From Omabe Festival In Nsukka, Enugu State.
The truly amazing people of Ibagwa-ani in Nsukka LGA of Enugu State arrived on the scene in mass to celebrate their Omabe festival. The Ooduarere reader who took the picture wrote “I took my time for you to snap some of the masquerade for future use. It had been each day of joy, I was heading to a one village for my video shoot before I saw them.. Enjoy.”
See more pics after the page break
Ngozi Nwosu lori eto Gbajumo Osere
Ayo Ab’ara Bintin
Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun wa wipe Eledua fi Omobinrin lantalanta da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Olori AJOKE GOLD OLUWAKEMI ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata.
A wa ngba ni adura wipe, a ti mo ibere omo yi, a o ni mo opin re lase Edumare. Aisan ti n se iya omo leyin ibi omo ko ya nile lodo yin ni oruko Oluwa. Gbogbo ohun ti e nilo lati fi to omo yi ti yoo fi je eniyan laye ni Eledua yoo fi s’eke yin.
Ki Olodumare wa wo ola omo tuntun jojolo yi, gbogbo eda ti nwoju Oluwa fun ohun ayo bayi ki oba mi oke wa dawon lohun ni kia lase Edumare.
OLORI AJOKE GOLD GBOGBO EBI OMO YORUBA ATATA NILE-LOKO ATI LEYIN ODI NKI YIN WIPE, E SI KU OWO LOMI O!
Fun anfani awa ti a fe pe iya omo lati ki won a le pe won sori ero ibanisoro yi.
ODO
EJO
ODO
ETA
ARUN
ESAN
ETA
ESAN
ARUN
EJO
ODO
`Abel Simeon Oluwafemi