Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ...

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC) Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀gá àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀ lórilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Brig. Shuaibu Ibrahim ti sàlàyé fún...

View Article


Ọrẹ Fálọmọ , Irúnmọlẹ̀ Ìṣègùn Tó Dáńtọ́ Nínú Ìràn Oòduà(Yorùbá) Wọ Káàlẹ̀ Lọ

Ọrẹ Fálọmọ , irúnmọlẹ̀ ìṣègùn tó dáńtọ́ nínú ìràn Oòduà(Yorùbá) wọ káàlẹ̀ lọ Fẹ́mi Akínṣọlá Hùn! Báakú làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Ni báyìí, gbogbo ọmọ Oòduà(Yorùbá) ló tí ń sun rárà ọlọ́kan ọ̀...

View Article


Kùkùlajà Ètò Ààbò, Gani Adams Ní OPC Àtàwọn Míì Ṣetán Láti Ṣiṣẹ́ Pẹ̀lú...

Kùkùlajà ètò ààbò,Gani Adams ní OPC àtàwọn míì ṣetán láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ elétò ààbò nílẹ̀ Yorùbá Kùkùlajà ètò ààbò,Gani Adams ní OPC àtàwọn míì ṣetán láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ elétò...

View Article

About Isefa, Itefa, Idafa, Ise Ifa/Akose.

Isefa is to receive one hand of Ifa. This only happens if due to one reason or the other, the person could not be initiated at that present time and it’s important for such person to have Ifa at that...

View Article

The translation of the “Ọ̀run” as “heaven” is totally misleading – Prof. Moyo...

It turns an indigenous Oòduà (Yoruba) concept upsidedown into an Abrahamic tradition of “heaven” and “hell.” The Christians and Moslems attempted to distort the Oòduà (Yoruba) language to serve their...

View Article


Kogi àti Bayelsa ìdìbò gómìnà gbọdọ̀ lọ nírọwọ́ rọsẹ̀.. ..Ààrẹ Buhari

Kogi àti Bayelsa ìdìbò gómìnà gbọdọ̀ lọ nírọwọ́ rọsẹ̀.. ..Ààrẹ Buhari Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ko ko ko là á ránfá adití,àti pé ó ń bọ̀, ó ń bọ̀,ojú ni wọ́n ń mú tó o. Èyí ló mú kí Ààrẹ orílẹ̀ yìí Muhammadu...

View Article

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba – Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ,bí Ọlọ́run bá rí ọ, jéèyàn náà ó sẹ̀ríìrẹ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi...

View Article

Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu

Ìdájọ́ Ilé ẹjọ́ kò sọ pàtó ẹni tó jáwé olúborí láàrín Makinde àtiAdelabu Fẹ́mi Akínṣọlá Kángun kàngùn Kángun, bọ́ pẹ́,bọ́ yá, ó gbọ́dọ̀ kángun síbìkan, bẹ́ẹ̀ ló súmọ́ kí ọ̀rọ̀ rí ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́,...

View Article


Àsepò̩ tó dán mó̩rán wa láarin èmi ati àwo̩n èèyàn O̩yo̩ – Gómìnà

Èmi àti àwọn èèyàn Ọyọ yóò máa fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ológun.. Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé inú dídùn ń ni yoòbá níí mórííya àti pé yiinínú,níí jẹ́ kẹ́ni fẹ́ ṣèmìí. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀...

View Article


Stumbles upon this in my library, so I decided to edit and share the...

The Ifa’s Ethical Commandments according to Ika-OfunIká funfunA d’ifá fun agbaagba MerindinlogúnThis was Ifa’s message for the 16 Elders.Won n rele lfe won n lo reé toro ogbóThey went to Ile Ife to...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Si afirmas que Ifa ya no está en África porque durante la Era del comercio de...

Como historiador, permítanme aclarar esto rápidamente. Durante la era del comercio de esclavos, solo hombres y mujeres capaces fueron llevados mientras que los viejos se quedaron atrás. Espero que...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ìkòkò Ọ̀ṣun, Àkòdì Òrìṣà

Orisa Artists building a gigantic ikoko (pot) of Osun, at the Akodi Orisa, Ile Ife, Nigeria. Ìkòkò Ọ̀ṣun, Àkòdì Òrìṣà

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Review: iPhone/Android Ifa Apps for consultation

I have lost counts of Ifa Apps on iPhone store and android play store. I will just review all of them in this post, this way people will not be fooled by many of this shame Apps. First of all,...

View Article


Obi ni n bi arun

AboruAboyeAbosise..Ifa niiiiii Obi ni n bikuObi ni n bi arunObi ni n bi ofoObi ni n bi gbogbo ibi.Olodumare abawa fi obi biku, bi arun, bi ofo, bi gbogbo ajogun ibi aye wa o.Ase edumare. Sponsored by...

View Article

Happy Ose Egúngún today to you all.

Egúngún yodà, gbogbo AwoEgúngún yodà, òtá kòleè gbé inú ilé móEgúngún ti yodà gbogbo Awo~ Ìwòrì gósùn Egúngún brought out a sword, all Priests and PriestessesEgúngún brought out a sword, the enemies,...

View Article


Invocation Of The Spirit Of Wisdom – Orunmila

Ẹyẹ kan fò lórí omi, lórí omi, ó f’apá ọ̀tún ba’lẹ̀, ó ró gbọ́ngbọ́ngbọ́n bí ọkọ́ A bird twirls all over the water, landing with her right wing, and sounding as does the hoe when struck. Ẹyẹ kan bà...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Photos: Agògòrò Èyò in Sao Paulo Brazil

Oodua (Yoruba) culture and heritage is very rich.Eyo is to honour our Ancestors.I had to join the Eyo in a dance at the celebration of Egbe Omo Oduduwa in Brazil 30th November 2019 especially being a...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ẹ̀rìndínlógún

Artist: Moyo OkedijiTitle: Ẹ̀RÌNDÍNLÓGÚNDate: 2017

View Article

They were celebrating Egungun festivals and this happened In Iseyin.

“They were celebrating Egungun festivals joy and happiness. The fanatics among the Muslims attacked them that they are agent of “devil” so they won’t allow them celebrate their festival in peace. They...

View Article

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbé Soworẹ lásìkò tí ó fi ń léwájú ìwọ́de “Revolution now”.Ìtúsílẹ̀ rẹ̀ ń wáyé lẹ́yìn tí ó ti lo ọjọ́...

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live