Quantcast
Channel: Art Archives - Ọmọ Oòduà
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live

O̩kùnrin àkó̩kó̩ lórí Te̩lifísò̩n l’Áfíríkà filè̩ bora

Bí Kunle Ọlasọpe, ìlúmọ̀ọ́ká agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ṣe lo ìgbésí ayé rẹ̀ rèé o. Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ wọ́n níjọ́ a kú,làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. ọrun dẹ̀dẹ̀ má kánjú gbogbo wa la ń bọ̀.Olóògbé...

View Article


Sun Re O: Alagba The 344 Years Old Tortoise In Ogbomoso, That Has Outlived...

View Article


Image may be NSFW.
Clik here to view.

Feliz y bendecido Ojo’se Ifá.

Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Feliz y bendecido Ojo’se Ifá. Buenas noches Òlódumarè y todos los Irunmoles les bendigan, dentro de nuestras creencias el estar en alineación con...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Odu, “Òtùá Yèpín (Òtúá yèkú)”- cast for today’s Ose Ifa

Looking at the Odu, “Òtùá Yèpín(Òtúá yèkú)” cast for today’s Ose Ifa, what else can we ask from Elérìí Ìpín, Witness to Destiny, if not favourable destiny. Just listen to the stanza Òtúá yèpín wóò adé...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Oriki Ori

Ori Onise Apere Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori ni seni ta a fi lo...

View Article


Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́

Igbákejì gómìnà Ọyọ ní Ladọja ṣe bẹbẹ lẹ́ka ètò ẹkọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ìgbésẹ̀ òhun ìhùwàsí oníkálùkù láàyè, ìtàn ló ń kọ lóké eèpẹ̀.Tẹbi tara tọ̀rẹ̀ àti àwọn èèkan nísẹ́ Ìjọba ló péjú láti ṣé ajọyọ̀...

View Article

Yẹ Kí Nàìjíríà Dín Iye Àwọn Sẹ́nétọ̀ Tó Ń Ṣojú Wọn Kù Tàbi, Ka Kúkú Pa Ipò...

Ó yẹ kí Nàìjíríà dín iye àwọn Sẹ́nétọ̀ tó ń ṣojú wọn kù tàbi, ka kúkú pa ipò náà rẹ́ …..Gomina ìpínlẹ̀ Ekiti Fẹ́mi Akínṣọlá Ó ní àwọn sẹ́nétọ̀ tí ń náwó tó pọ̀jù léyìí tí Ìjọba yí le fi owó náà ṣe...

View Article

Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀

Ìjọba ṣe tán láti bẹ̀rẹ̀ sí ní gbowó orí lóri ìbáraẹnisọ̀rọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àbùùbùtán oore lọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ,fáwa ọmọ aádámọ̀,ọ̀làjú àsìkó yìí,ti fẹ́ mú kí nǹkan ó gbọ̀nà ọ̀tun yọ,bí...

View Article


Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’

Àyájọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ ló kò yìí, kín làkíyèsí ẹ̀yin obìnrin lórí àìsàn jẹjẹrẹ ọyàn Fẹ́mi Akínṣọlá Ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Kẹwàá ọdọọdún ni àyájọ́ ọjọ́ ‘Má wọ kọ́mú’ lorilẹede Nàìjíríà eyi tó ń sọ fún àwọn...

View Article


Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì- NLC

Àfikún owó oṣù nìkan lẹ̀rọ̀ ìyanṣẹ́lódì…NLC Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ lorilẹede Nàìjíríà, NLC, ti sọ fún àwọn adari ẹgbẹ́ ọhun láwọn ipinlẹ pé kí wọ́n gbaradi fún ìyanṣẹ́lódì, bẹrẹ láti ọjọru, ọjọ...

View Article

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe wọ́n ní yini yini kí ẹni le sèmí ì ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,nígbà tíIgbákejì Ààrẹ ilẹ wa, Ọ̀jọ̀gbọ́n...

View Article

Iṣẹ́ ìránṣẹ́ kò sí fún ìmẹ́lẹ́ èèyàn – Tunde Bakare

Fẹ́mi Akínṣọlá Ayé ló bàjẹ́ tí ọmọ olè ń dájọ; oníkálukú mọ ẹ̀tọ́ tó yẹ́’.Olùṣọ́ àgùtàn Tunde Bakare ṣàlàyé bí ìdámẹ́wàá ṣe bẹ̀rẹ̀ ninu Bíbélì àti pé kò si ẹni tí wọ́n gbé ìbọn tì pé dandan ni kó san...

View Article

Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ?

Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ? Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé kò sí ìlú tí kò ní àdámọ́ ọ ti ẹ̀. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí nílùú Igbóọrà .Igbóọrà jẹ́ ìlú kan tó kalẹ̀ si agbègbè Ìbàràpá...

View Article


Àsírí Òkété

ÒKÉTÉ.___Òkété jẹ́ ọ̀kan nínú ẹranko abàmì tó lágbára púpọ̀. A sì máa gbé nínú ihò. ELÉDÙMARÈ fún-un ní àṣẹ púpọ̀.Òkété kìí fi ọwọ́ tàbí ẹṣẹ̀ gbẹ́ ihò, ÌRÙ ni òkété maá n fií gbẹ́ ihò, fún ìdí èyí, ẹ...

View Article

Yoruba does not exist in Ifa ― Elebuibon

By Shina Abubakar – Osogbo A renown traditionalist and the Araba of Osogbo, Chief Ifayemi Elebuibon said prior to contact with the Hausa/Fulani, the race is known as the people of Ife, saying it is...

View Article


llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́

llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní ilé tí a fi itọ́ mọ, ìrì ni yóò wo. Ọbẹ̀ tí a fi èké pilẹ̀ ẹ rẹ̀, í í ru paná ni bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀...

View Article

Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú mi – Aláàfin Ò̩yó̩

Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá...

View Article


Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se –...

Ẹ ẹ̀ ṣi nọ́ńbà mú l’Ọyọ, gbogbo owó yín tí mo bá ná, ẹ ó rí n tí mo fi se…..Seyi Makinde Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí Ọlọ́run bá sẹ̀rí ì rẹ,jẹ́ kí èèyàn náà ó sẹ̀rí ì rẹ .Gomina ìpínlẹ̀ Ọyọ, Onímọ̀...

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Oríkì Obàtálá

Ọbàtálá ọbátárìsàỌba pátápátá tí ń bá wọn gbóde iránjéỌba nílé Ifọ́nÒ sùn nínú àlàÒ jí nínú àlàÒ tí inú àlà dìdeÒrìṣà wun mi ní budoIbi Ire l’òrìsá kalẹ Akú òsè Obàtálá O kettle drum

View Article

Image may be NSFW.
Clik here to view.

Ase !

Ase ! Orisa has spoken !  Àṣẹ́ o Ase wa

View Article
Browsing all 2260 articles
Browse latest View live